Not Only For Your Enemy

THE SEED

“Whoever digs a pit may fall into it; whoever breaks through a wall may be bitten by a snake…” Ecclesiastes 10:8-9 NIV

Most of the time we Christians make use of the above opening bible verses as a divine weapon against our enemies and adversaries that might be causing us discomfort to make progress in life. In as much as this is appropriate, it is also true that we might be at the wrong side or receiving end of the same scripture. If as Christian we are not careful or apply wisdom
to deal with situations in our relationship with other Christians we might be unconsciously digging a pit for others or attacking a helpless child of God and this will expose one to the
fulfilment of the scripture. A perfect example of this scenario is the situation in which King David found himself after listening to the message of God through Prophet Nathan. King David ignorantly jumped to the conclusion of giving judgment over the rich man that had everything but took the only lamb that belonged to a poor man to entertain his visitor. King David, a man after God’s heart, became vulnerable to receiving the negative penalty. As a child of God, we will be walking into a trap if we allow sin to push us into doing and saying unacceptable things to others, especially Christians.

PRAYER

Father in Jesus’ name, help me to walk in wisdom, knowledge, and truth to avoid hurting people around me. Amen

BIBLE READINGS: 2 Samuel 12:1-10

KII SE FUN OTA RE NIKAN

IRUGBIN NAA

“Eni ti o wa iho ni yio bo sinu re, ati eni ti o si n ja ogba tutu, ejo yio buu san, Enikan ti o nyi okuta, ni yio si ti ipa re ni ipalara, ati eni ti o sin la igi ni yio si wu li ewu.” – Oniwaasu 10:8-9

Opo igba ni awa onigbagbo maa nlo ese Bibeli yii gege bi ohun ija si awon ota ati awon ti nse lodi si wa, ti won le maa dena atise rere wa laye. Bi eyi ti dara to, o tun see se ki ese Bibeli yii ki o maa ba awa funra wa wi. Gege bi Kristeni, bi a ko ba kiyesara, tabi ki a fi ogbon ba awon onigbagbo bii tiwa lo, o see se ki a maa wa iho fun awon eniyan laimo tabi ki a maa koju ija si omo Olorun, eyi si le mu ki ese Bibeli yii ki o se mo wa lara. Apeere daradara ni ti oba Dafidi, nigba ti o gbo ise ti Olorun ran si lati enu Woli Nathani. Oba Dafidi fi aimo yara lati se idajo fun oloro ti o ni ohun gbogbo sugbon ti o mu omo agutan tii se ti talaka lati fi se alejo okunrin ti o to o wa. Oba Dafidi, eni bi okan Olorun, o di eni to ngba idajo buburu,
Gege bi omo Olorun, bi a ba gba ese laye lati ti wa sinu sise ati siso ohun ti ko dara si omonikeji, a o bo sinu idekun, paapaa julo awa Kristeni.

ADURA

Baba ni oruko Jesu, ran mi lowo lati rin ninu ogbon, oye ati otito, kin ma baa maa se awon ti o yi mi ka. Amin

BIBELI KIKA: II Samuel 12:1-10

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *