The Right Time

THE SEED

“For the vision is yet for an appointed time, but at the end, it shall speak, and not lie: though it tarry, wait for it, because it will surely come, it will not tarry”. Habakkuk 2:3

There is time for everything in this world as the writer of the book of Ecclesiastes said: “To everything, there is a season and a time to every purpose under the heaven.” Eccl 3:1.
A man’s life is in phases of time in which different event takes place. Right from the physical and emotional development of a child, there is a certain age at which a baby is
expected to crawl when it is not yet time to walk. You don’t expect a baby of 6 months to be running around. Sometimes we have not gotten what we desire or pray for when it is not yet
time to have it. God does things at the right time. The time at which what we ask for will suit us and will be so satisfying is when they will get to us. Things gotten at the appropriate time are lasting and do put our minds at rest. When a man walks and works at the right time of his life, He will look more like a genius, knowing what to do at the time because he understands the right time.

PRAYER

May we understand our divine timing so that we can wait for the appropriate time in every season of our lives and take full advantage of it. Amen

BIBLE READINGS: Habakkuk 2:2-3

ÀKOKÒ TÍ O TỌ

IRÚGBÌN NÁÀ

“Nitori iran na jẹ ti igbà kan ti a yàn, yio ma yára si igbẹhìn, kì yio si ṣeke, bi o tilẹ̀pẹ, duro dè e, nitori ni dide, yio de, kì yio pẹ. ” Hab 2:3 BM

Gégé bíi iwe Oniwasu ti sọ, àkokò wa fún ohun gbogbo ninu ayé yìí “Olukulùku ohun li akoko wà fun, ati ìgba fun iṣẹ gbogbo labẹ ọrun.” Oniwasu 3:1 Igbesì ayé eniyan wa ni ìpele-ìpele àkokò ti awọn iṣẹlẹ kan mã nṣẹlẹ. Nipa idagbasoke ọmọde ninu ara, ọjọ ori kan wa ti a nireti wipe ki omo ọwọ ma fà. Yíò jé ohun àjèjì lati nireti pe ki omo osú mẹfa ma sáré kiri. Nigba míràn, ọwọ wa kò tíì tẹ ifẹ inu wa tabi esi ádùrá wa tabi ki a gbàdúrà fún un lai tii to àkokò. Ọlọrun a maa ṣe ohun gbogbo l’akoko ti o tọ. Àkokò tí yíò dára fún wa, ti yio si tẹ wa lọrùn ni won yíò tẹ wa lọwọ. Awọn ohun tí a ba ri gba l’àkoko ti o tọ ma n jẹ ajẹmonu ati ohun ifọkanbalẹ, ti eniyan ba n ri ti o si n ṣíṣe ni àkokò tirẹ, yíò dabi eni to ni imo nítorípé àkokò rẹ ni o n lo.
ÁDÙRÁ

Oluwa, é fún mi ni imọ lati le ṣiṣẹ pẹlu àkokò mi nigba ayé mi, láti lo bi o ti yẹ. Amin.

BIBELI KIKA: Habakuk 2:2-3

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *