You’re Priviledged To Be In God’s Presence

THE SEED

“Do you not know? Were you not told long ago? Have you not heard how the world began? It was made by the one who sits on His throne above the earth and beyond the sky; the people below look as tiny as ants. He stretched out the sky like a curtain, like a tent in which to live.” Isaiah 40:21-22 GNT
Beloved of Christ, when we’re in the presence of the Creator of the earth and heaven, the owner of our lives and all mankind, it’s such a great privilege and grace which should be
managed with reverence and uttermost care. In the reality of things, we shouldn’t be anything before God, considering His creative power, and His habitation. We are surely like tiny ants who
need Him for our existence than He needs our worship. If we think of it, there are heavenly beings who don’t bother God with unlimited requests as we humans do. They worship Him
without ceasing and with no divided attention. So, for this magnificent God to set time aside to listen to us that are full of transgressions and vainglory, we must understand that it’s a great privilege received through the grace of Jesus Christ His Son, who died for us to seal the work of reconciliation, and we must be careful that this must not be trampled upon.

PRAYER
Lord, let your Spirit fill me and make me understand the privilege of being in Your presence. Amen

BIBLE READINGS: Psalm 8:3-9

O NÍ ÀNFÀNÍ LÁTI WÁ NÍWÁJÚ ỌLỌRUN

IRÚGBÌN NÁÀ

“Ẹnyin kò ti mọ̀? ẹnyin kò ti gbọ́? a kò ti sọ fun nyin li atètekọṣe? kò iti yé nyin lati ipilẹṣẹ aiye wá? On ni ẹniti o joko lori òbíri aiye, gbogbo awọn ti ngbe ibẹ si dabi ẹlẹngà; ẹniti o
ta ọrun bi ohun tita, ti o si nà wọn bi àgọ lati gbe.” Isaya 40:21-22 BM

Ayanfẹ Kristi, nigbati a ba wà níwájú adẹda ayé àti ọrún, ẹnití o jẹ alakoso èmí wa ati ohun gbogbo, o jẹ anfani nla ati ore-ofe ti a ni lati bọwọ fún. Bi o ṣe yẹ ki o ri, a ko jẹ ohunkohun níwájú Ọlọrun bí a ba wo àgbàrá iṣẹda rẹ̀ati ibugbé rẹ̀, a dàbí ẹlẹngà ti o nilō Ọlọrun fún iwalaye wa jù bi Ọlorun ṣe nilo ìsìn wa mọ. Bi a ba gbē yẹwo, awọn ogún òrun wà ti wọn ko bēre fun ohunkohun lọwọ Ọlọrun bikoṣepe ki wọn maa júbà rè lai dúró pẹlú ọkàn kan. Nitorina, ti Ọlọrun ti o tóbi bayi ba le fi àyè sílẹ láti f’eti sí awa ti a kún fún ìrékọjá ati ògo asan, o gbọdọ ye wa pe eyi jẹ anfani ti a ri gba ninu ore-ofe ti Jesu Kristi, omo rẹ̀, eniti o kú fún wa láti ṣe iṣẹ ìlàjà, a ni lati ṣọra ki anfani yi maṣe di ohun ìtẹmolẹ.

ÁDÙRÁ

Oluwa, je ki emi rẹ fún mi ní òye láti mọ ànfàní- ìwà níwájú rẹ̀. Amin.

BIBELI KIKA: Orin Dafidi 8:3-9

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *