THE SEED
“Blessed is the man whose quiver is full of them. They will not be put to shame when they contend with their opponents in court.” Psalms 127:5
Children are a heritage from the Lord, allotted to each family by divine order and to serve a purpose. In what way have you been a useful weapon for your family? Do you tarnish or uphold the image of your family with your attitudes, speech and actions? Children are meant to be productive to achieve, not useless or stagnant. The children as arrows must be carefully guided for aiming straight. Lay claim to the blessings and defend the honour of your family. It is a great blessing to have them. They will occupy places of prominence wherever they are making their marks and prosperity will follow them. If you have been fortunate to be guided rightly by your parents; retain your spots, be on guard to stand with your parents. As God’s heritage, aim to be an achiever who will stand against your family’s accuser and keep their mouth shut.
PRAYER
Father, help me to live my life as your heritage to my parents.
BIBLE READINGS: Psalm 127:3-5
INI OLUWA
IRUGBIN NAA
“Ibukun ni fun okunrin naa, ti apo re kun fun won. Oju ki yio ti won, sugbon nwon o según awon ota li enu ona.” Orin Dafidi 127:5.
Omo ni ini Oluwa, ti o fi sinu idile kankan gege bi agbekale Olorun ati lati wa se ise pataki kan. Ona wo ni o ti gba je ohun elo ti o wulo fun idile re? Nje o n ba oruko idile re je tabi o n tunse pelu iwa, oro ati ise re? Gege bi omo, o ye ki o sise ki o si jere, ki o se aseyori. Ko ye ki o ma wulo tabi ki o wa loju kan naa. Gege bi ofa alagbara, a gbodo to awon omo sona ti o to. Gba ibukun, ki o si gbe oruko idile re ga. Ibukun nla ni o je lati ni omo. Nwon o de ipo giga nibkibi ti nwon ba de, nwon o si se rere. Ti o ba ni anfani wipe awon obi re to o sona ti o to, mase ya kuro ni ibe, duro ti awon obi re. Gege bi ini Oluwa, lepa lati je alaseyori, eniti n ja fun idile re, to si le pa awon ota yin lenu mo.
ADURA
Baba, ran mi lowo lati le gbe igbe aye mi gege bi ini Oluwa si awon obi mi. Amin
BIBELI KIKA: Orin Dafidi 127:3-5