Owe No Man

THE SEED
“Owe no man anything, but love one another, for he that loveth another hath fulfilled the law.” Romans 13:8.

Many people will find the first phrase from this scripture unbelievable considering the economic crisis that every people from different phase of life do face. Some people go through some financial challenges in the course of meeting their basic needs like putting food on their tables, wearing cloth and putting a decent roof on their heads. Most people will say how can they survive this without borrowing from others or without owing people? How can they survive on their meagre salary in the face of huge financial demands? You as a believer should come to this full understanding that when your Father in heaven lays a demand on you, He has equally made a full provision and grace for you to live by it. When the scripture says owe no man. That means God is able to provide for your needs to such an extent that you will not need to borrow money from others. You will live in the abundance in Christ Jesus, lacking nothing good in life. Believe this and it shall be yours in
Jesus name. It is love for others that you will never be able to repay back completely till eternity.

PRAYER
Oh Lord, may I live in the abundance of Your riches and blessings and may I owe no man except love.
BIBLE READINGS: Romans 13: 6-10

MASE JE ENIKENI NIGBESE

IRUGBIN NAA
“E mase je enikeni ni gbese ohun kan, bikosepe ki a feran omonikeji eni, nitori eniti o ba feran omonikeji re, oko ofin ja.” Romu 13:8

Opolopo eniyan ni ipele akoko ninu eko ti a ka yii yio soro fun lati gbagbo nitori isoro oro aje ti opolopo eniyan ndojuko nibi gbogbo. Awon elomiran nkoju isoro ailowo lojuna ati pese ohun kosemani fun ara won bi ounje, aso, tabi ile. Opolopo ni yio wipe, bawo ni mo se le se awon nkan wonyi lai yawo lowo enikeni tabi je enikeni ni gbese? Bawo ni owo osu won ti o kere se le to lati gbo bukata nla iwaju won? Gege bi onigbagbo, o ye ki o mo wipe niwon bi Baba re ti mbe ni Orun ti pa eyi lase fun o, o ti seto ibukun fun o ni ekun rere. Nigba ti iwe mimo wipe ki a mase je enikeni lowo, o tumo si wipe Olorun lagbara lati pese fun aini re to bee ge ti iwo ki yio tun ni lati toro owo lowo enikeni. Iwo yio si maa gbe ninu ekunrere ti Kristi Jesu, iwo ki yio tun se alaini ohun rere kan mo laye. Gba eyi gbo, yio si je ipin re ni oruko Jesu. Ife si omonikeji nikan ni o ko le san tan lae lae.

ADURA
Oluwa, je ki nma gbe ninu ekun rere oro ati ibukun re, ki nmasi je enikeni ni igbese bikose ife.
BIBELI KIKA: Romu 13: 6-10

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *