Watch What You Say

THE SEED
“Let no corrupts communication proceed out of your mouth, but that which is good to the use of edifying, that it may minister grace unto the hearers.” Ephesians 4:29.

In the world today, many people say whatever they want to say and anyhow they want to say it. Foul language fills the social media and in the public, there is nothing tagged as a word of shame again. It depends on the reigning slangs. What we say from our mouths mark us and shows who we follow. It tells people who is in charge of our lives, whether it is God or Satan? We have been instructed if we profess to be a Christian that we should make a conscious decision that foul language will not come out of our mouth no matter what. We should be careful that bad or wrong phrases or statements should not proceed out of our mouth. Do not join others to say filthy words. The Lord can help us to have a renewed heart from which good words that are filled with grace can come out of. Remember that you are a temple of the living God if you are His child. So the words of your mouth should be holy.

PRAYER
Let the words of my mouth, and the meditation of my heart be acceptable in thy sight, O LORD, my strength, and my redeemer.
BIBLE READINGS: James 3: 1-12

KIYESI ORO ENU RE

IRUGBIN NAA
“E mase je ki oro idibaje kan ti enu yin jade, sugbon iru eyiti o dara fun eko, ki o le maa fi ooreofe fun awon ti ngbo.” Efesu 4:29

Ninu aye loni, opo eniyan a maa so ohun ti o wu won ati bi o ti wu won. oro alufansa kun ori ayelujara ati ni igboro, ko tile si ohun ti won npe ni oro itiju mo. Oro to ba ti gba igboro kan ni won yio tun maa so. Awon oro to n ti enu wa jade, a maa fi iru eniyan ti a je han, a si maa toka si eniti a n tele. O n juwe eniti n se akoso aye wa, bi Olorun ni tabi esu. Ati palase fun wa niwon igba ti a ba pe ara wa ni onigbagbo, pe awon oro ti ko fogo fun Olorun ko gbodo ti enu wa jade bi o ti wu ki o ri. Ani lati kiyesara ki oro odi tabi oro buburu mase ti enu wa jade, kia mase dara po mo awun eniyan aye lati maa soro to lumo ese. Oloruun le ran wa lowo, ki a le ni okan titun lati inu eyi ti oro ti o kun fun ooreofe yio ti maa jade wa. Ranti wipe tempili Olorun alaaye ni iwo nse bi o ba je omo Olorun. Nitornaa, awon oro enu re gbodo je mimo.

ADURA
Je ki oro enu mi, ati isaro okan mi, ki o se itewogba li oju re, Oluwa, agbara mi ati oludande mi.
BIBELI KIKA: Jakobu 3: 1-12

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *