All Because I’m Special

THE SEED
“And being in an agony he prayed more earnestly: and his sweat was as it were great drops of blood falling down to the ground.” Luke 22:44

In the garden of Gethsemane, hours before He died, Jesus knelt down to have a discussion with His Father. For quite a long time, Jesus walked in this world, the Father’s central goal was His mission. He just talked and went about as His Father guided Him. As He expected the Cross, He begged God that, assuming it was possible, assuming there was another way, if it is not too much trouble, to let this cup pass from Him, and if not, that God’s will be fulfilled. His agony was so much that he prayed and His sweat dropped as a thick blood trickling from His face. He drained for you since He has faith in you. At His Word, everything was formed. The sun ascends in the east and sets in the west since Jesus instruct it to do as such. The moon sparkles at His command. He has numbered and named the stars, instructing them to sparkle for His purpose. He framed each mountain with His hand. He cut each valley with His finger. He established each bloom. He planned each animal. However, He drained for not even one of them. He didn’t drain for the trees or the birds. He didn’t drain for the large numbers of angels. He drained for you since He has faith in what He made you to be.

PRAYERS
Father Lord, let not your pain on the cross of Calvary go in vain over my life and family, let me remain special among the saints in Jesus name.

BIBLE READINGS: Luke 22: 39-46
NÍTORÍPÉ ÈMI JẸ PÀTÀKÌ
IRÚGBÌN NÁÀ
“Ati ti bi o ti wa ninu irora o gbadura siwaju sii kikankikan: òógùn rẹ̀ si dabi iro ẹ̀jẹ̀ nla, o nkan silẹ.” Luku 22: 44.

Ninu ọgba Getsemane, awọn wakati ṣaaju ki o to ku, Jesu kunlẹ lati ba baba rẹ jiroro. Fun igba pipẹ, Jesu rin ninu aiye yii, Èròngbà baba rẹ ni ero Rẹ. O kan nwàásù o si nlọ bi Baba rẹ ti
nṣe amọna rẹ. Bi o ti nreti agbelebu, Ó bẹ Ọlọ́run, nígbà tí ó nrò pé ó ṣeé ṣe, tí ó si nrò pé ọ̀ nà mìíràn wà; bí kò bá pọ̀ jù loju Bàbá rẹ kí ó jẹ́ kí ago yìí kọjá lórí òun, bí bẹ́ẹ̀ kọ́ , kí ìfẹ́ Ọlọ́run ṣẹ. Írora rẹ̀ sì pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́, o sì ngbà adura to bẹ́ẹ̀ tí o fi jẹ́ pé òógùn rẹ̀ nkan silẹ bi iro ẹ̀jẹ nla ti o nṣàn li oju rẹ̀. O si nṣàn fun ọ nitoriti o ni igbagbọ́ ninu rẹ: nitori ninu ọ̀rọ rẹ̀ li a ti dá ohun gbogbo: õrùn gòke lọ si ìha ìla-õrùn, o si wọ̀ ni iwọ-õrun, nitori Jesu ti paṣẹ fun u lati ṣe bẹ̃. Oṣupa nmọlẹ li aṣẹ rẹ̀: o ti kà wọn, o si sọ awọn irawọ, ní orúkọ, o sì pàṣẹ fun wọn láti máa tàn fún èrò Rẹ̀. O da awọn òke kọọkan pẹlú ọwọ Rẹ̀. Ó fi ìka rẹ̀ gé àfonífojì kọ̀ ọ̀ kan. O fí ìdí itansan kọọkan múlẹ. O pète ẹran kọọkan. Sibẹsibẹ ko ró ẹjẹ Rẹ fun ọkan ninu wọn. Kò kan ẹjẹ Rẹ̀ silẹ fún igi tàbí fún àwọn ẹyẹ. Tàbí yala fun ọpọlọpọ awọn angẹli. O tá ẹjẹ sílẹ fun ọ niwon igbati o ni igbagbo ninu ohun ti o dá ọ fún.

ADURA
Baba Oluwa ma jẹ ki irora rẹ lori agbelebu Kalfari lọ lasan lori aye ati idile mi, jẹ ki n duro ni pataki jùlọ laarin awon eniyan mimo ni oruko Jesu Àmín

BIBELI KIKA: Luku 22: 39-46

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *