THE SEED
“Wherefore gird up the loins of your mind, be sober, and hope to the end for the grace.” 1 Peter 1:13
There are different trials that we face in our daily lives as we encounter different kinds of frustrations, disappointments, contradictions, privations, sickness, and all sorts of hardships. All these things cause pain both physically and psychologically. However, patience is defined as our efforts to handle them courageously without losing our serenity, or without being so irritated or despondent. To be patient therefore means to endure discomfort without complaint. Patience involves such things as self-control, humility, and generosity, all of which are themselves virtues. So, one might say that patience is a virtue because it’s an exercise of several other virtues. Dearly beloved, as believers, we should have the courage to endure much more if these hard times can be seen in the perspective of the cross of Christ. We must be intentional about increasing our patience by focusing ever more clearly on the example of Christ to imitate Him in all things, large and small.
PRAYER
O Lord give me patience in times of tribulations. In Jesus name I pray, Amen
BIBLE READINGS: James 1: 2-8; Isaiah 40: 27-31
EMI SUURU
IRUGBIN NAA
“Nitorinaa, e di okan yin ni amure, e maa wa li airekoja, ki e si maa reti oreofe ni titi de opin, eyiti a nmu bo fun nyin wa ni igba ifarahan Jesu Kristi.” 1 Peteru 1: 13
Oniruuru ni awon wahala ti a n koju lojoojumo aye wa bi ati n ri orisirisi idamu, ijakule, iselodi, aini, aisan, ati awon inira. Gbogbo eyi a maa mu inira wa nipa ti ara ati nipa ti okan. Sugbon suuru ni igbiyanju wa lati la awon ohun yii koja pelu igboya, lai baraje, lai ni irira tabi ja kule. Sise suuru tunmo si fiforiti inira lai kun. Suuru ni ikora eni ni ijanu, irele, isoore ati awon ti o je iwa rere. Olufe owon, gege bi onigbagbo, o ye ki a ni igboya lati tunbo foriti ti a ba wo igba irora Kristi lori igi agbelebu. A gbodo mu ki suuru wa ki o po si nipa wiwo apeere Kristi, ki a wo awokose re ninu ohun ti o kere tabi ti o tobi.
ADURA
Oluwa, fun mi ni suuru ni igba isoro. Ni oruko Jesu ni mo gba adura. Amin
BIBELI KIKA: Jakobu 1: 2-8; Isaiah 40: 27-31