Forgiveness Of Sins

THE SEED
“Praise the Lord, my soul, and forget not all his benefits—who forgives all your sins and heals all your diseases.” Psalm 103:2-3

We don’t always like to bring up the topic of sin. But in our life of faith it’s necessary to face up to our desperate predicament. Sadly, many believers refuse to act the way they should towards God, others, themselves, and God’s creation. We persistently choose to disregard our maker, contend with others,
deceive and harm ourselves, and mistreat creation. Sin does not only lead to trouble and misery but also proves that we rightfully deserve punishment. Through His atoning sacrifice, Jesus washed away our sins. Even though we may continue to struggle with sin, Jesus assures us that God will not
judge us as we deserve because we have been forgiven. The forgiveness of sins stands at the core of following Jesus. Because we have been
for-given, we can, through the power and help of the Holy Spirit, strive each day to faithfully serve Jesus. As he gave himself for us, with thanksgiving we can live for Him.

PRAYER
Halleluyah! Am grateful because I found Jesus

BIBLE READINGS: Ephesians 4

IDARIJI ESE

IRUGBIN NAA

“Fi Ibukun fun Oluwa iwo okan mi ma si se gbagbe gbogbo ore re. eniti o dari ese re ji o ti o si tan gbogbo arun re.” Orin Dafidi 103:2-3

Ao kii fe so oro nipa ese sugbon ninu igbe aye igbagbo wa, o ye ki a dojuko isoro naa. O ba ni ninu je wipe a o wu iwa bi o ti ye si Olorun, si elomiran, si ara wa ati si oun ti Olorun da. a yan lati se aibikita eleda wa, a nba ara wa jijakadi, a ntan ara wa, a si tun nse arawa ni ijamba. Kiise wahala ati idaamu nikan ni ese ma nmu wa, o ma nmu ijiya ti o ye wa. Jesu se awenumo ese wa nipa eje re. bi a se njijakadi pelu ese, Jesu fi dawa loju wipe Olorun ko ni dawa lejo bi o se to siwa nitori wipe ati ri idariji. Idaraji ese je oun ti o se Pataki ninu titele Jesu. Nitori a ti ri idariji, a le maa tiraka lati sin
Jesu lotito lojoojumo nipase agbara ati iranlowo Emimimo.

ADURA
Oluwa, Halleluyah, mo dupe wipe mo pade Jesu

BIBELI KIKA: Efesu 4

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *