THE SEED
“You keep track of all my sorrows. You have collected all my tears in your bottle. You have recorded each one in your book.” Psalm 56:8, NLT
Do you have any idea that you mean a lot to God? He thinks and cares a lot about everything related to your life. He thinks often about your viewpoints, emotions and feelings. As a matter of fact, what you are going through is so critical to Him that He records each distress and gathers the tears you’ve shed. Why would God record your sorrows and collect your tears? Because everything that affects you matters to Him. He is your Vindicator. He’s keeping an account of every wrong that’s ever been done to you so that He can make up for every single one of them. He wants to restore to you everything that has ever been stolen. He wants to heal every hurt and pain. Today, know that God cares about the things that concern you. He cares about the things that hurt you. He is close to the broken-hearted, and He wants to bring you peace and comfort. Turn to Him and receive His love. Let Him bring healing to your heart and restoration to your soul.
PRAYER
Father, thank You for loving me and setting me free. Thank You for being my vindicator. I choose to release every hurt, pain and sorrow, knowing that You will make all things new in Your time in Jesus’ name. Amen.
BIBLE READINGS: Psalm 56
O KO GBOGBO ẸKÙN RẸ PỌ
IRÚGBÌN NÁÀ
“Iwọ nla irinkiri mi: fí omije mi sinu igo rẹ: nwọn kò ha sì nínú ìwé rẹ bí?” Psalmu 56:8
Njẹ o tilẹ mọ pé o ni ìtumọ púpọ sí Ọlọrun? O máa n ronú làti tọjú ohun gbogbo tí o ní ṣe pẹlú ayé rẹ. O ronu nigbagbogbo nipa awọn oju-iwoye, awọn ẹdun ati awọn ikunsinu. Ni otitọ, O mọ ohun ti o n la kọja o ṣe pataki sí í, ti O fí ṣe akọsilẹ ipọnju kọọkan, ati pe o ko awọn omije ti o ti ta silẹ jọ. Kini idi ti Ọlọrun yíó fí ṣe ní àkọsílẹ̀ ibanujẹ rẹ àti akojọpọ omije rẹ? Nitoripe ohun tí o bá ṣẹlẹ sí ọ kan an. O jẹ alagbawi rẹ. O ni àkọsílẹ ohun ti a ṣe lòdì sí ọ ki o ba le ṣe àtúnṣe rẹ̀. O fẹ dá ohun ti a gba lọ kúrò ní ọwọ́ rẹ pàdà. O fẹ lati ṣe ìwòsàn ọgbẹ ati ìrora. L’oni, mọ pé Ọlọrun nbojuto ohun ti o nṣe tirẹ. O nṣe abójútó ohun ti o bá fẹ pa ọ lára. O wá ní tosí awọn onirobinujẹ ọkàn, O sì fẹ fún ọ ní àlàáfíà àti ìtùnú. Yípadà síi kí o ṣi gbà ìfẹ Rẹ. Gbàá láàyè kí o mú ìwòsàn bá àyà rẹ̀ àti imu dúró bá ọkàn rẹ̀.
ÁDÙRÁ
Baba mo dupẹ fún ìfẹ ti ẹ ni sí mi. E ṣeun pé Ẹ jẹ alagbawi mí. Mo yan lati fi ọgbẹ, ìrora àti ìbànújẹ mi silẹ ni idaniloju pe Ẹ o sọ ohun gbogbo dì títún ni akoko yin. Ni orúkọ Jésù Àmín.
BIBELI KIKA: Psalmu 56