Do You Recognize It?

THE SEED
“His divine power has given us everything we need for a godly life through our knowledge of him who called us by his own glory and goodness.” 2 Peter 1:3, NIV

When something great occurs, do you perceive that it’s God working? Immediately, that is the point at which you really want to say thanks to Him for it. Ensure you give Him the credit. Certain individuals don’t believe that God is doing anything in their lives. You must be convinced that God is continually showing us His goodness. The question is: Are you aware of it? Is it safe to say that you are saying thanks to Him for His goodness? This week, look around. Be more
aware of His goodness. Scripture says, “Oh, taste and see that the Lord is good.” If you’re going to taste God’s goodness, you have to realize that every good break, every time you were protected, every door that opened, every advantage that you’ve had is God working in your life. Don’t take it for granted. Recognize Him and thank Him for His goodness and faithfulness all the days of your life!

PRAYER
Father, today I am on the lookout for Your goodness. I honor and thank You for Your love. I praise You because You are faithful and glorify You in everything I do in Jesus’ name. Amen.

BIBLE READINGS: 2 Peter 1

NJẸ O DAA MỌ

IRÚGBÌN NÁÀ
“Bí agbara Rẹ, bi Ọlọrun ti fún wa li ohun gbogbo ti ṣe tí ìyè àti tí ìwà- bí-Ọlọrun, nipa ìmọ ẹnití o pé wá nipa ògo ati ọlánla Rẹ.” 2 Peteru 1:3

Nigbati ohun nla kan bá ṣẹlẹ, njẹ o ní òye pé Ọlọrun nṣe iṣẹ? Lọ́ gán, ní irú akoko bayi ní o nilo lati wipe Ọlọrun ṣeun. Rí wipe o fún ùn ní gbogbo ìyí. Àwọn ènìyàn kan kò gbágbọ́ pé Ọlọ́run nṣe ohun-kohun ninu ayé wọn. O yẹ ki o ní ẹrí ìdánilójú pé Olúwa nfí réré hàn fún wá nigbagbogbo. Ibere kàn nìyí: Njẹ o mọ nipa rẹ? Njẹ o tọna lati sọ pé O ṣeun fún ìre tí a nri gba lọwọ Rẹ? Lọ́ sẹ̀ yí, wò, yika, jẹki ire Rẹ di mímọ fún ọ. Ìwé mímọ sọ pé, ” Tọ ọ wò ki o sì rí pe réré ní
Oluwa”. Tí o bá fẹ lati tọ ìre Olúwa wo, o gbọdọ mọ pé gbogbo igba ní a nda abo bo ọ, gbogbo ilẹkùn tí o bá ṣi, gbogbo anfààní tí o bá ní mọ wípé Olúwa ní o nṣiṣẹ ninu ayé rẹ. Maṣe ai náà ní rẹ. Da Ọlọrun mọ, ìre àti òtítọ Rẹ, ni gbogbo ọjọ ayé rẹ.

ÁDÙRÁ
Baba lóni mo nwa ìre Rẹ, mọ bi ọlá fún Ọ mo tun dupẹ fún ìfẹ Rẹ. Mo yín Ọ l’ogo nítorí O jẹ olóòótọ, mo sí ṣe Ọ l’ogo nínú ohunkohun ti mo nṣe. Ni orúkọ Jésù Àmín.

BIBELI KIKA: 2 Peteru 1

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *