THE SEED
“…and should sleep by night and rise by day, and the seed should sprout and grow, he does not know how…” Mark 4: 27 NKJV
Beloved of Christ please be encouraged. Keep feeding yourself with the Word of God, walking in faith and love, and fellowshipping with the brethren. These will enhance your spiritual growth and development, You may not see or feel it, but you are growing and becoming stronger spiritually. And when trials and challenges come (as they must), you will find out that you are not the same person you were yesterday. God is doing mighty work in you. You are the Growing Seed. Each challenge of life you face and overcome takes you to another level of growth, it increases your level of perseverance, patience, and faith in God, .. even though you may not be aware of being moulded into this new individual that is full of understanding, knowledge and power of God just like the growth of the scattered seed could not be measured but remember always that you are growing in the Lord to become a better person in His Kingdom.
PRAYER
Heavenly Father I thank You that Your power is working in me. Making me a better person day by day. Have Your way in my life, in Jesus’ name Amen.
BIBLE READINGS: Mark 4:26-29
OWE IRUGBIN TO N DAGBA
IRUGBIN NAA
“Kí ó sì sùn lóru, kí ó sì dìde ní ọ̀sán, irúgbìn náà yóò sì hù jáde, yóò sì dàgbà, kò mọ̀ bo se n…” Máàkù 4:27
Mokanle. Máa bo ara rẹ pẹ̀lú Ọ̀rọ̀ Ọlorun, ní rírìn nínú ìgbàgbo àti ìfe, àti ìjosin pẹ̀lú àwọn ará. Iwọnyi yoo mu idagbasoke àti itesiwaju rẹ pọ si ni ti ẹmi, O le ma ri tabi lero rẹ, ṣugbọn o n dagba, o si tun ni okun sii nipa ti ẹmi. Nigbati idanwo ati awọn idojuko ba de (bi wọn ṣe gbọdọ), iwọ yoo rii pe iwọ kii ṣe eniyan kanna ti o jẹ lana. Olorun nse ise nla ninu re. Iwọ ni Irugbin ti n dagba. Gbogbo awon ipenija ti o ba dojuko nínú aye, ti o si bori yoo mu ọ lọ si ipele idagbasoke miiran. O mu ipele sũru rẹ, ati igbagbọ ninu Ọlọrun pọ si, … Bi o tilẹ jẹ pe o le ma mọ wipe àti mo o sinu ènìyàn oto yi, eyi ti o Kun fun oye, imo ati agbára Ọlorun gege bí ìdàgbàsókè irúgbìn tí a ti fon ká ti kò ṣe e díwọ̀n, ṣùgbon rántí nígbà gbogbo pé ìwọ ń dàgbà nínú Olúwa láti di ènìyàn tí ó dára jùlọ nínú Ìjọba Rẹ̀.
ADURA
Baba ọrun Mo dupẹ lọwọ Rẹ pe agbara Rẹ nṣiṣẹ ninu mi, ti o mu mi dara si lojoojumọ. Ṣé oludari aye mi ni oruko Jesu Amin.
BIBELI KIKA: Máàkù 4:26-29