Accept The Right To Become God’s Child

THE SEED
“But to all who did receive him, who believed in his name, he gave the right to become children of God,” John 1:12 ESV

Becoming God’s child is the only key that gives access to both legitimate earthly and heavenly treasures. Why? Because God is the creator and owner of both domains! Jesus Christ is the only heir through whom we receive the spirit of sonship that gives divine access to becoming a joint heir with Him. What are the requirements? Just receive Jesus and believe in him. Mind you these are two different things. To receive is to accept while belief is established in trust. It is possible to receive and not believe, total belief in Christ makes our receiving Him a legitimate act before God, an action that compliments and approve our sonship birth. So where are you in this process? Have you just received Christ, but still believe in other things? If this is the situation then you have not started the process of fulfilling the requirements and you need to make up your mind now because there’s not much time left. And if you have received Christ and believe in Him with total trust, keep the fire burning and be vigilant that no one takes your crown. Remember that Rehab the harlot received the spies of Israeli and trusted in the God of Israel, she was adopted by the family of Israel and this gave her a place in God’s Kingdom.

PRAYER
Lord Jesus, I pray that you help me to receive you and continue to believe in you till the end.
BIBLE READINGS:  Joshua 2:8-13

 GBA ETO LATI DI OMO ỌMỌLORUN

IRUGBIN NAA
ùgbon gbogbo àwọn tí ó gbà á, tí won gba orúkọ rẹ̀ gbo, ó fi àẹ fún láti di ọmọ Ọlorun.” Jòhánù 1:12

Kilode ti eniyan ko fi fun ararẹ ni aye lati di ọmọ Ọlọrun? Didi ọmọ Ọlọrun ni kokoro kanṣoṣo ti o funni ni aye si awọn ohun iyebiye ti ọrun. Kí nìdí? Nitori Olorun ni Eleda àti alakoso aye àti orun. Jesu Kristi ni arole kanṣoṣo nipasẹ ẹniti a gba ẹmi jijẹ-ọmọ ti o funni ni anfaani àtorunwá lati je arole Lati ba joba. Kini awọn oun ti a nilo? Iwo saa gba Jesu, ki o si gbagbo. Nje Iwo mo pe awon meji yi yàto si arawon? Lati gba nkan tumo si ki a ma ko. Beeni igbagbọ wa  ninu igbẹkẹle. O ṣee ṣe lati gba ki a ma si gbagbọ. Igbagbọ tokantokan nínú kristi lo mu gbigba a wa je oun ti o bofinmu niwaju Ólorun, eyi ti o je iwà to fowosi ni jije omo. Ibo lo wa nínú Ilana yi? Nje o se gba kristi tabi o si gbàgbo nínú awon nkan Miran? Ise to Nitorina nibo ni o wa ninu ilana yii? Ti o ba je iru ipo ti o wa niyi, a je wipe o o ti bere igbese Lati ni awon amuye, o ni lati se ipinnu bayi tori kosi akoko púpo mo.  To ba je pe o ti gba kristi, ti o si gbàgbo nínú re tokantokan, ma a tesíwájú nínú sise be, ki o si kiye Sara, ki elomiran ma ba a gba ade re. Rántí pé Réhábù aṣewó gba àwọn afimufinle omo Ísírelì, ó sì gbeke lé Ọlorun Ísírelì, ìdílé Ísírelì gbà á, èyí sì fun ni àyè nínú Ìjọba Ọlorun.

ADURA
Jesu Oluwa, Mo gbadura pe ki o ran mi lọwọ lati gba ọ ati tẹsiwaju lati gbagbọ ninu rẹ titi di opin. Amin
BIBELI KIKA: Jóṣúà 2:8-13

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *