THE SEED
“The Lord is on my side; I will not fear. What can man do to me?” Psalms 118:6 NKJV
As a child of God, there is no reason to fear anyone more than Him because God has power and authority over everything and everyone. Whenever the situations of life put us in a place where we need to choose between God and man, no matter how terrifying it may be our allegiance must be to God who in return can turn the situation around. Fear God at all times even at the point of death, he will always make a way and you will never regret depending on Him, the three Hebrews Meshach, Shadrach and Abednego faced with death still refused to bow to the idols of King Nebuchadnezzar, they were thrown into the furnace but came out triumphantly. Also, Daniel, continued to pray to God Almighty, he was thrown into the lion’s den, but he was saved by the Power of the highest God. let the fear of God reign in your life and God will take care of the man on your behalf.
PRAYER
Lord, please grant me the Grace to fear you in all my endeavours and realize that you are bigger than all life-threatening situations in Jesus Name.
BIBLE READINGS: Psalm 118:6-14
BERU ỌLORUN JU ENIYAN LO(2)
IRUGBIN NAA
“Oluwa mbe pelumi mi; Emi ki yoo bẹru. Kí ni ènìyàn lè ṣe sí mi?” Ìwé Orin Dafidi 118:6
Gẹgẹbi ọmọ Ọlọrun, ko si idi lati bẹru ẹnikẹni ju Ólorun lọ nitori pe Ọlọrun ni agbara ati aṣẹ lori ohun gbogbo ati gbogbo eniyan. Nigbakugba ti a ba ba Ara wa nínú idamu aye nibi ti a o ti yan laarin Ọlọrun ati eniyan, bi o tiwu ki o buruto ,yinyan wa gbudo je ti Ólorun eni ti o le yi idamu wa pada si rere. Bẹru Ọlọrun ni gbogbo igba paapaa ni oju iku, yoo la ọna nigbagbogbo ati pe iwọ ki yio kabamo pe o gbekelé. Awọn Heberu mẹta Meṣaki, Ṣadraki ati Abednego dojuko iku sibẹ won kọ lati tẹriba fun awọn oriṣa Nebukadnessari Ọba, wọn ju won sínú ìléru, ṣùgbon won jáde wá pẹ̀lú ìṣegun. Pẹ̀lúpẹ̀lù, Dáníelì tesiwaju láti gbàdúrà sí Ọlorun Olódùmarè, a sọ o sínú ihò kìnnìún, ṣùgbon a gbà á là nípasẹ̀ Agbára Ọlorun Ọ̀gá Ògo. Je ki iberu Olorun joba ninu aye re, Olorun yoo si toju okunrin naa nitori re.
ADURA
Oluwa, jowo fun mi ni oore-ofe lati beru re ninu gbogbo akitiyan mi, ki n si mo wipe o tobi ju gbogbo ipo eewu l’oruko Jesu.
BIBELI KIKA: Ìwé Orin Dafidi 118:6-14