Fulfilling Purpose

THE SEED
“For we are His workmanship, created in Christ Jesus unto good works, which God hath before ordained that we should walk in them.” Ephesians 2:10

Every human being on the surface of the earth was born for a purpose and this is so because God does not do anything just for the sake of doing it; there is always a purpose behind His actions. If God has put you in this world, then there is a purpose for your life. Unfortunately, many are leaving the life of others and by so doing they end up not fulfilling their purpose in life. You can ask many people today why are they leaving the lifestyle of smoking, drinking and womanizing and many more. They don’t realise that It’s the influence of others in their life. There are certain features that God has built into you as your talents and gifts. You need to discover them and then go back to God to tell you what they were built into you to do. If you are ready to make sacrifices just so that you can impact the lives of other people positively, then you are on the path to fulfilling your purpose. The lives you impact, the souls you win for Christ and your good works will be recorded in heaven (Revelation 20:12) That is all that will matter after you are gone from this world. According to the scripture above, How many people have you done good works for recently?

PRAYER
Father help me I am ready to work in the part of fulfilling my purpose in life.
BIBLE READINGS:  Ephesians 2:6-10

  MIMU ERONGBA SE

IRUGBIN NAA
“Nítorí àwa ni ie ọwo re, tí a dá nínú Kristi Jesu fún àwọn ie rere, tí Ọlọrun ti yàn tele, kí á lè máa rìn nínú wọn.” Éfésù 2:10

Gbogbo edá ènìyàn lórí ile ayé ni a bí fún idi kan, èyí sì rí be e nítorí pé Ọlorun kì í ṣe ohunkóhun nítorí ṣíṣe é lásán; nigbagbogbo idi kan wa lẹhin awọn iṣe Rẹ. Tí Ọlorun bá fi o sínú ayé, ìdí kan wà fún ìgbésí ayé rẹ. Ó ṣeni láàánú pé opọ̀ èèyàn ló ń gbe igbe aye elomiran nípa ṣíṣe be e, wọn ò ní mú ete ìgbésí ayé wọn ṣẹ. O le beere lọwọ ọpọlọpọ eniyan loni kilode ti wọn fi n gbe igbe aye siga mimu, oti mimu ati agbere sise ati bebelo. Wọn ko mo wipe, igbe aye elomiran lo n dari igbe aye tiwon. Awọn amuye kan wa ti Ọlọrun ti da sinu rẹ bi awọn talenti ati awọn ẹbun rẹ. O nilo lati ṣawari wọn ati lẹhinna pada sodo Ọlọrun lati sọ fun ọ ohun ti a da sinu rẹ lati ṣe. Ti o ba ṣetan lati pinu pe, iwo yio ni ipa rere Nínú aye awọn eniyan miiran, eyi tumo si wipe o mu ayanmo re se. Awọn igbesi aye ti o ranlowo, awọn okan ti o jere fun Jesu ati awọn iṣẹ rere rẹ ni a o kọ silẹ ni ọrun (Ifihan 20:12). Iyẹn ni gbogbo ohun ti yoo ṣe pataki lẹhin ti o ti lọ kuro ninu aye yii. Gẹgẹ bi iwe-mimọ ti o wa loke, eniyan melo ni o ti ṣe rere si lakoko yi?

ADURA
Baba ran mi lọwọ,Mo ṣetan lati ṣiṣẹ kin le mu ete mi se ninu aye.
BIBELI KIKA: Éfésù 2:6-10

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *