When Man Says No

THE SEED
“And you shall say to him, ‘The Lord God of the Hebrews has sent me to you, saying, “Let My people go, that they may serve Me in the wilderness”; but indeed, until now you would not hear!” Exodus 7:16 NKJV

Some adamant enemies are so confident with the evil powers that they believe that they can do whatever pleases them, they usually boast that ‘once they say no way to someone then it is a done deal. Is this true when such boasts have to do with you as a child of God? The answer is a definite no. Because as a child of God your life is hidden in Christ and christ’s in God’s so no such boasts can affect you if you have not been careless to give them room to exercise their evil authority. As long as you are on the Lord’s side, who said and it comes to pass when the Lord has not approved it, it will always be a no for them and a yes from God that you serve, for our God is a consuming fire, the fire seen burning the bush but alas! the bush did not burn. Let them know that you serve the Great man in battle, the only God of Israel that can fight and win battles without ammunition. Do not be afraid of them but pray fervently and serve the Almighty God genuinely with all your hearts, you will laugh and they shall cry and regret it all.

PRAYER
I pray that all the adamant enemies of progress in my life shall be ruthlessly dealt with in Jesus’ Mighty Name. Amen
BIBLE READINGS:  Exodus. 14:21-28

NIGBA TI ENIYAN BA SO WIPE BEEKO

IRUGBIN NAA
Ki iwọ ki o si wi fun u pe, Oluwa Ọlọrun awọn Heberu li o rán mi si ọ, wipe, Jẹ ki awọn eniyan mi ki o lọ, ki nwọn ki o le sìn mi li aginjù; ùgbon ní tòóto, títí di ìsinsìnyí, ìwọ ko gbo!” Ẹksodu 7:16 KJV

Àwọn otá kan tí won je Olori kunkun ní ìgboya pelú àwọn agbára ibi débi tí won fi gbà pé àwọn lè ṣe ohunkóhun tó bá tẹ́ àwọn lorùn. Won sábà máa ń fonu pé ti won ba tile so wipe ko si onà fun ẹnikeni, bee na ni yoo ri. Ṣé òóto ni èyí nígbà tí irú ìgbéraga bee ní í ṣe pelú rẹ gege bí ọmọ Ọlorun? Idahun re ni wipe; BEEKO. Nítorí gege bí ọmọ Ọlorun, ìwàláàyè rẹ wà nínú Kristi àti ti Kristi nínú Ọlorun,nítorí náà iru ihale bee kò lè nípa lórí rẹ bí o kò bá bìkítà láti fún wọn láyè láti lo àṣẹ ibi wọn. Níwon ìgbà tí eyin bá wà ní ìhà odọ̀ Olúwa tí ó soro, ti o si wa si imuse, ko si ihale ti otá le se, ti yio wa si imuse. Nítorí Ólorun wa, Ina ajonirun ni. Iná  ti o njo igbe ti igbe ko si run. Je kí won mo pé o n sin Ólorun alagbara lójú ogun, Ọlorun Ísírelì kan ṣoṣo tí ó lè jà, tí ó sì lè ṣegun láìsí ohun ìjà. Maṣe bẹru wọn ṣugbọn gbadura gidigidi ki o sin Ọlọrun Olodumare nitootọ pẹlu gbogbo ọkan rẹ, iwọ yoo rẹrin ati pe wọn yoo sọkun ati kabamọ gbogbo rẹ bi Farao.

ADURA
Mo gbaladura pe gbogbo awon ota ilosiwaju ninu aye mi ni a o segun won ni oruko nla Jesu. Amin
BIBELI KIKA: Eksodu. 14:21-28

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *