Evangelism

THE SEED
And He said unto them, Go ye into all the world, and preach the gospel to every creature Mark. 16: 15 KJV

As children of God and ambassadors of Christ we need not enjoy the grace of God alone but share with others that have not experienced the love of Him that redeemed us. It’s a privilege we had and we should therefore act as though God were making his appeal through us to propagate the gospel. We must win souls. In Isaiah 61: 1, the Bible says; the Spirit of the Lord GOD is upon me; because the Lord hath anointed me to preach good tidings unto the meek; he hath sent me to bind up the brokenhearted, to proclaim liberty to the captives and the opening of the prison to them that are bound for the Son of man is come to seek and save that which was lost for there is joy in Heaven over a sinner that repented. There are a variety of ways to evangelize to unbelievers.We can employ the sermon, tracts, door-to-door, lifestyle, friendship and child evangelism to mention but a few.

BIBLE READING: Mark 16:12-18

PRAYER: Oh Lord my Father, I pray that you grant me the grace to propagate the Gospel giving others room to enjoy your Faithfulness. Amen.

IHINRERE

IRUGBIN NAA
O si wi fun wọn pe, Ẹ lọ si gbogbo aiye, ki ẹ si wasu ihinrere fun gbogbo eniyan. Marku 16:15 KJV

Gẹ́gẹ́ bí ọmọ Ọlọ́run àti àwọn ikọ̀ Kristi a kò ní láti gbádùn oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run nìkan ṣùgbọ́n pínpín pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn tí wọn kò tí ì ní ìrírí ìfẹ́ Ẹni tí ó rà wá padà. Ore-ofe ni a ni atí wipe a gbudo wuwa bi eni pe, Ọlorun n kosi wa lati polongo ihinrere re nípase wa. A gbudo Jere okan. Isaiah 61:1. Bibeli wipe; Ẹ̀mí OLUWA Ọlọrun bà lé mi; nitori Oluwa ti fi ami ororo yàn mi lati wasu ihinrere fun awọn onirẹlẹ; o ti rán mi lati di awọn onirobinujẹ ọkan, lati kede ominira fun awọn igbekun, ati ṣiṣi tubu fun awọn ti a dè nitori Ọmọ-eniyan ti n no wá ati gba eyi ti o sọnu là, nitori ayọ̀ mbẹ li Ọrun lori elese ti o ronupiwada. Awọn ọna oriṣiriṣi wa lati ṣe ihinrere fun awọn alaigbagbọ. A le se ipolongo ojuledojule, pinpin fonron, igbe aye wa, ibadore atí wiwasu si awon omode atí bebelo.

BIBELI KIKA: Marku. 16:12-18

ADURA: Oluwa Baba mi, Mo gbadura pe ki o fun mi ni oore-ọfẹ lati polongo Ihinrere re kaakiri fifun awọn miiran ni aye lati gbadun Otitọ rẹ. Amin.

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *