OPEN, ILLUMINATED

THE SEED
“I pray that the eyes of your heart may be enlightened … that you may know the hope to which he has called you…” Ephesians 1:18

What a blessing it is to read this prayer of the apostle Paul. He asks that God will open, or enlighten, the eyes of our hearts. Why? That we may “know him better,” to have “the Spirit of wisdom and revelation,” and know the hope of all that God promises to us. With hearts open to the wonder of all that God has done, we are empowered by His Spirit to live faithfully for him, as Jesus did. When we are open to God’s working in and through our lives, we are like a blank page on which He writes his poetry, an empty canvas on which he works His artistry, softened clay with which He moulds his vessel. Perhaps the right combination is openheartedness and singlemindedness—our heart and mind equally devoted to the God of infinite wisdom.

BIBLE READING: Ephesians 1:17-23

PRAYER: Jesus, encourage us in the single-minded pursuit of being open to your wisdom and your working in our lives. In your name we hope. Amen.

IMỌLẸ OJÚ Ọ̀KAN WA

IRUGBIN NAA

“Mo gbàdúrà kí ojú ọkàn yín lè mọlẹ; ki ẹyìn kì o le mọ ohun ti ìrètí ipe rẹ jẹ, àti ohùn tí ọrọ ògo ìní rẹ nínú àwọn ènìyàn mímọ jẹ.” Efesu 1:18

Ìbùkún ńlá ló jẹ́ láti ka àdúrà àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù yìí!  Ó béèrè pé kí Ọlọ́run ṣí, tàbí tan ìmọ́lẹ̀, ojú ọkàn wa.  Kí nìdí?  Kí a lè “mọ̀ ọ́n daradara,” kí a lè ní ẹ̀mí ọgbọ́n àti ìṣípayá,” kí a sì mọ ìrètí gbogbo ohun tí Ọlọ́run ṣèlérí fún wa. Pẹlu ọkàn tí o ṣe awọn ohùn àrà tí Ọlọrun ti ṣe; a fún wá ní agbára Ẹ̀mí lati gbé nínú òtítọ fún ùn bí Jésù tí ṣe. Nigba ti a ba ṣi ọkàn wa sí Ọlọrun nipa bi O tí nṣiṣẹ  Rẹ̀ ninu aye wa;  a o da bi iwe tí a kò kọ ohunkohun sí órí rẹ, ti a pèsè silẹ láti kọ ìtàn ati  akọsilẹ le lori. Amọ̀ tí o rọ̀ lati fi ṣe iṣẹ amọ̀koko rẹ. Bí ohun àpapọ ti o tọ, jẹ ọkan ti o ṣi paya tabi ọkán kan, ẹmi wa ati ọkàn wa gbọdọ wà ní ìbámu pẹ̀lú Ọlọrun wa.

BIBELI KIKA: Efesu 1:17-23

ADURA: Jesu gba wa niyanju ninu ilepa ọkan-kan  si ọgbọn Rẹ tí o sí n ṣiṣẹ ninu igbesi aye wa.  L‘orukọ Rẹ  ni a ní ìrètí Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *