THE SEED
“But your iniquities have separated between you and your God, and your sins have hid his face from you, that he will not hear.” Isaiah 59:2
The scripture above gives us one clearly stated reason for God’s unwillingness to answer our prayers: our sin. Every person is born on the “sin side” of the wall, and every person will stay on the sin side of the wall until they go through the Door of Jesus’ Blood and Forgiveness. No one is born on the Jesus side of the wall. You don’t automatically “jump” from the sin side, to the other side of the wall without knowing it or without finding and entering through the Door! And that takes a process—a process of finding the Door and deciding to go through the door. Our greatest need is to find the Door in the wall. Jesus meets that need! He says to the heart searching for that door, “I am the Door. I don’t just show you a door, I AM THE DOOR. I’m the only door to the Father’s Heart and only by passing through Me, can you be cleansed and forgiven of your sin.
BIBLE READING: Isaiah 59
PRAYER: Lord, I acknowledge that I am on the right side of wall by accepting You as my Lord and Savior.
OJU MEJI NI OGIRI NI
IRUGBIN NAA
“Ṣugbọn aiṣedede nyin ni o fa iyapa lãrin iwọ ati Ọlọrun nyin, ati awọn eṣẹ nyin ti pa oju re mo kuro lara nyin, ti on ki yio fi gbo.” Aísáyà 59:2
Iwe-mimọ ti o wa loke fun wa ni idi kan ti o sọ kedere fun aisetan Ọlọrun lati dahun adura wa nitori ẹṣẹ wa. Olukuluku eniyan ni a bi ninu ese ati pe gbogbo eniyan yoo duro ni egbe Ogiri ese titi wọn o fi gba ẹnu-ọna Ẹjẹ Jesu ati idariji koja. Ko si eni ti a bi sinu Jesu kristi. Iwọ ko jade kuro ninu ẹṣẹ sinu iye biko se wipe o gba enu onà igbala koja. Eleyi gba ìgbése, ìgbése wiwa enu onà naa atí pipinnu Lati gba a koja. Ibeere ti o tobi julọ ni lati wa onà na a. Jesu ti pese eyi síle. Ó sọ fún ọkàn tó ń wá ilekun naa pé, “Èmi ni ilekùn náà. Emi ko kan fi ilẹkun na han ọ lasan, Emi ni ilẹkun naa. Emi ni onà kan soso si Okan Baba ati nipa gbigba odo mi nikan soso koja, ti si le ri idariji gba.
BIBELI KIKA: Isaiah 59
ADURA: Oluwa, mo gba pe mo wà ní apá otún ògiri ní isinsìnyí nípa gbígba Jésù Krístì gege bí Olúwa àti Olùgbàlà.