Hard Times Are Here

THE SEED
For with God nothing shall be impossible.” Luke 1:37

The current situation is real and hard, but it is not impossible to fix according to the scripture above. As long as you are a Christian, you must make up your mind to take the WORD of GOD, the Bible literal. The Bible says that nothing is impossible. In other words, your hard times are not impossible for GOD to handle or turn around. Believe this! This is the first step in dethroning your hard times and bringing it down to its normal size. Don’t buy the lie from the devil that your situation is beyond repair. It is a lie. All problems are solvable based on the proper application of the WORD of GOD. As difficult as your situation is, it is still under the rulership of the MOST HIGH. No problem of life is STRONGER than GOD. No hard time is higher than GOD. No challenge is superior to GOD. Don’t quit and give up. It is not your portion. In life combat, someone must either win or give up and lose. As long as you don’t quit, the devil and his problems will have no choice but to quit and get out of your life.

BIBLE READING: Luke 1

PRAYER: Unto you my family and I put our trust in you O LORD help us overcome this hard times Amen

ÀKOKO ISORO TI DE

IRUGBIN NAA
“Pelú Ọlorun, Gbogbo oun ni ṣi ṣe.” Lúùkù 1:37

Tòóto ni pe ipo ti o wa lọwọlọwọ le ṣugbọn ko ṣee ṣe lati bori re pelú oun ti iwe-mimọ loke yi so. Níwon ìgbà tí o bá je Kristẹni, o gbodo pinnu láti mu Oro Ọlorun ninu Bíbélì lo. Bíbélì sọ pé kò sí ohun tí kò ṣeé ṣe. Lonà miran, awọn akoko isoro rẹ ko sọrọ se fun Ọlọrun Lati yi pada. Gba eyi gbọ! Eyi ni igbesẹ akọkọ lati yanju awọn isoro rẹ, ki o si so di yepere. Maṣe gba irọ lati ọdọ eṣu pe isoro rẹ ko ni atunṣe. Iro ni. Gbogbo awọn iṣoro ni o ni iyanju ni ibamu pelú ỌRỌ ỌLỌRUN. Bó ti wù ki isoro re le to, ó wà lábe ìṣàkóso ogá Ògo jù lọ. Ko si isoro aye ti o lagbara ju OLORUN lo. Ko si akoko lile ti o ga ju OLORUN lọ. Ko si ipenija to ga ju OLORUN lọ. Maṣe sa, ma si je ko sun o. Kii ṣe ipin tirẹ. Ninu Ogun aye, ẹnikan gbọdọ ṣegun, ki enikan si padanu. Niwọn igba ti o ko ba sa, eṣu ati awọn iṣoro rẹ kii yoo ni sai fi aye re síle.

BIBELI KIKA: LUKU 1

ADURA: Emi ati idile mi gbeke wa le O OLUWA ran wa lowo lati bori asiko lile yi Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *