THE SEED
“Above all, taking the shield of faith, wherewith ye shall be able to quench all the fiery darts of the wicked.” Ephesians 6:16
The reality of the present day is that we are surrounded by some highly contagious diseases that threaten the welfare of our families and being. We’re not talking of AIDS, EBOLA, COVID-19 and STD’s, but rather, we are constantly exposed to social diseases every day. We are exposed to hate crimes, racial profiling, sexual harassment, injustice and political corruption. However, the solution is making our faith more contagious and sustaining than those diseases. We need a faith that will get us through tough and turbulent times. Therefore, to have a sustaining faith we must not forget our Lord. No matter where we are and what we are going through. In the boardroom, workplace or classroom; in the midst of difficulties or during times of growing pains – take the lord with you. When we pack up our briefcases and backpacks –we must take our God with us for the journey. No matter where we go, we are to take our faith with us. It will sustain us.
BIBLE READING: Ephesians 6
PRAYER: Help my Christian race O Lord that I may not fall unto the other side (HELL) Amen
IHAMORA IGBAGBO
IRUGBIN NAA
“Leke gbogbo re, e mu apata ìgbàgbo nipa eyití eyìn o le maa Fi Pana Gbogbo ofa Ina eni ibi ni” Éfésù 6:16
Otitọ ode oni ni pe, awon ajakale Arun ni o yi wa kaakiri eyití o n dojuko ebi atí ilera wa. A ko sọrọ nipa asian AIDS, EBOLA, COVID-19 ati STD, ṣugbon orisirisi Arun ni o dojuko wa lojoojúmo. Awọn iwa ikorira, ifipabanilopo,aiṣotito ati ibajẹ oṣelu ni a n dojuko. Bí ó ti wù kí ó rí, ona abayo ti a wa si awon idojuko wonyí ni o mu kí ìgbàgbọ́ wa túbo gbile si tí ó sì ń gbe ìgbàgbo wa duro ju àwọn àrùn wonyi lọ. A nilo igbagbọ ti yoo mu wa la awọn akoko lile ati rudurudu yi koja. Nítorí náà, láti ní ìgbàgbọ́ tí ń gbéni ró a kò gbọ́do gbàgbé Olúwa wa. Laibikita ibi ti a wa ati ohun ti a n la koja. Ninu yara igbimọ, ibi iṣẹ tabi yara ikawe; larin awọn iṣoro tabi lakoko awọn irora, jeki oluwa wa pẹlu rẹ. Nigba ti a ba pa awon eru irinajo wa mo, a gbọdọ mu Ọlọrun wa pẹlu wa fun irin-ajo naa. Ibi yòówù kí a lọ, a ní láti mú ìgbàgbọ́ wa pelú wa. Y’o gbe wa duro.
BIBELI KIKA: Éfésù 6
ADURA: Ran iran onigbagbo mi lowo Oluwa ki nma subu sinu Ina. Amin