Beyond Expectations

THE SEED
“Now unto him that is able to do exceeding abundantly above all that we ask or think, according to the power that worketh in us,” Ephesians 3:20

We all have things that we’re believing for, dreams to come to pass, problems to turn around. We’d be happy if they worked out our way, but sometimes what we have in mind is not God’s best. We think ordinary, God thinks extraordinary. We think, “Let me have enough to get by,” God thinks abundance. We think, “Let me manage this addiction,” God thinks freedom. We’re asking for the possible when God wants to do the impossible. He specializes in exceeding our expectations, and what he has in store for you is bigger, more rewarding, more fulfilling than you can imagine. You may have obstacles in your path and challenges coming against you today in your health, your finances, a relationship. You’re asking God to turn it around. Stay encouraged. God is not only going to bring you out, he’s going to have some spoils there. There is going to be some plunder. He’s going to bring you out better than you were before. He’s going to exceed your expectations. Never underestimate God’s power or goodness. He is able to do above our expectations.

BIBLE READING: Ephesians 3

PRAYER: Lord, help me to learn to accept Your work in my life. Help me to trust You.

JU BI A TI LERO LO

IRUGBIN NAA
“Nisinsinyi fun eniti o le se lọpọlọpọ ju ohun gbogbo ti a bère tabi ti a rò, gege bi agbara ti n sise ninu wa,” Efesu 3:20

Gbogbo wa ni o ni awọn nkan ti a n foju Sona si, awọn ala lati muṣẹ, awọn iṣoro lati yi pada. Inú wa yio dùn tí awon ireti wa ba wa si imuse, àmọ́ nígbà míì ohun tá a ní lọ́kàn kì í ṣe ohun tó dára ju lo ti Ọlorun fe fun wa. A wa maa ro oun yepere, Ọlorun maa n ro nla fun wa. A maa n ro wipe jeki n ni oun die ṣùgbon Olorun a ma ro opo yanturu. A maa n berẹ fun oun ti o ṣee ṣe nigbati Ọlọrun fẹ lati ṣe ohun ti ko ṣeeṣe fun wa. O n maa n ṣe oun ti o kọja ireti wa, ati pe ohun ti o ni ni ipamọ fun ọ tobi, o ni ere nla, o si teni lorun ju bi o ti lero lo. O le ni awọn idiwọ ni ọna rẹ ati awọn idojuko ti o nbọ si ọ loni ni ilera rẹ, awọn inawo rẹ, igbeyawo re. O n beere lọwọ Ọlọrun lati yi pada. Duro sinsin Kì í ṣe pé Ọlọ́run máa mú ọ jáde nìkan, ó máa bukun fun o. Idojuko die n mbo,Oun yoo mu ọ jade daradara ju bi o ti wa tẹlẹ lọ. Yio se se ju bi o ti lero lo . Má ṣe fojú tembelu agbára tàbí oore Ọlọ́run láé. O ni anfani lati ṣe ju awọn ireti wa lọ.

BIBELI KIKA: Éfésù 3

ADURA: Oluwa, ranmilowo lati kọ́ láti gba iṣẹ́ Ọlọ́run nínú ìgbésí ayé wa. Ranmilowo lati gbekele Yin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *