Accountanbility

THE SEED
“But if our unrighteousness commends the righteousness of God, what shall we say? Is God unrighteous who taketh vengeance? (I speak as a man)” Romans 3:5

The above scripture speaks about our unrighteousness. However, our unrighteousness reveals the righteousness of God. If we recognise our condition, it means there is a standard by which we gauge our actions and also accountable to the One who judges by that standard. The particular point that the Apostle makes in this verse is sobering for anyone who actually grapples with the thought that we must give an accounting to the One who is qualified by His inherent righteousness to judge. It means that we are held to a standard outside of our own condition and the benchmark for the pending judgement for all mankind. Thus, it should not be surprising that almost all the narratives constructed for millennia revolve around an attempt to evade responsibility for our own character. Ultimately, all narratives attempt to avoid facing our pending, and well-justified, judgement.

BIBLE READING: Romans 3

PRAYER: Let my life on earth be filled with your righteousness O LORD, forgive all my iniquity that I may have a good account in the Book of Life Amen

ISE IJINYIN

IRUGBIN NAA
“Ṣugbọn bi aiṣododo wa ba yìn ododo Ọlọrun, kili awa o wi? Ọlọrun ha jẹ alaiṣododo ti o gbẹsan bi?” Róòmù 3:5

Iwe-mimọ ti o wa loke sọrọ nipa aiṣododo wa. Sibẹsibẹ, aiṣododo wa fi ododo Ọlọrun han. Ti a ba mo irú ipo ti a wa, eyi yio je ki a mo pe gbendeke kan wa ti a o maa fi Dari ihuwasi wa, a o si mo pe awa yio jiyin fun onídájo. Kókó pàtàkì tí Àpọ́sítélì náà sọ nínú ẹsẹ yìí jẹ́ oun ti o teri Okan eni ba fún ẹnikẹ́ni tó bá ń bá èrò re mu ní ti tòótọ́ pé a gbọ́do ṣe ìjíhìn fún Ẹni náà tí ó koju osuwon nípa òdodo re láti ṣèdájọ́. O túmo sí pé a di opá-ìdiwon kan ní ìta ipò tiwa fúnra wa àti àmì ìdájọ́ tí ó n dúró fún gbogbo aráyé. Nitorinaa, ko yẹ ki o gbudọ jẹ iyalẹnu pe gbogbo itan akosile fun egbegberun odun da lori onà lati yera fun òjuse tàbí jiyin awon iwa wa.Ni ipari, gbogbo awọn itan-akọọlẹ ngbiyanju lati yago fun idajo ti n duro de wa lojo ikehin.

BIBELI KIKA: Róòmù 3

ADURA: Jeki aye mi kun fun ododo re OLUWA, dariji gbogbo aisedede mi ji mi, ki n le ni iroyin rere ninu Iwe iye Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *