THE SEED
“For as many of you as have been baptized into Christ have put on Christ.” Galatians 3:27
Baptism is the way in which believers testify to having entered into a personal relationship with Jesus. And the reason is so we might declare that since we have trusted in Christ’s death, burial and resurrection, we have victory over the flesh, the world and the devil. We declare we’re going to live differently, because Christ made us different within and we’re committed to expressing that difference throughout our lives. Have you been baptized since you believed? It’s not just a religious ritual, it’s a bold declaration. As a symbol, baptism visually re-enacts His burial in the grave and His resurrection to life. When we see a new believer walk into the water, go under the water, and come up from the water, we are seeing what Jesus did to save us. Baptism is a dramatic representation of Christ’s work of atonement (1 Cor. 15:1-4). Everything you need to walk in victory over sin has been provided! Commit today to living in the victory that was eternally won by Christ.
BIBLE READING: 1 Cor. 15:1-4
PRAYER: Lord, I commit today to living in the victory that was eternally won by Christ.
ÀKỌ́RI: ÌRIBOMI GEGE BI AMI
IRUGBIN NAA
“Nitoripe gbogbo yin ti a ti baptisi sinu Kristi ti gbe Kristi wo” Gálátíà 3:27
Ìrìbọmi jẹ́ onà tí àwọn onígbàgbọ́ ń jẹ́rìí sí pé wọ́n ti wọnú ibátan ti ara ẹni pelú Jesu. Ìdí sì ni pé kí a lè kéde pé níwon ìgbà tí a ti ní ìgbẹ́kelé nínú ikú Kristi, ìsìnkú àti àjíǹde, a ní ìṣẹ́gun lórí ẹran ara, ayé àti Esu. A n kede pe a o gbe igbe aye oto, nitori Kristi ti so wa deni oto atí pe o pinnu lati ṣe afihan iyatọ naa ni gbogbo ojo aye wa. Njẹ o ti ṣe baptisi lati igba ti o to gbagbọ? Kii ṣe aṣa ẹsin nikan, o jẹ ikede igboya. Gẹ́gẹ́ bí àmì, ìbatisí Fi íku ati ajinde Jesu han sí ìyè. Nigba ti a ba ri onigbagbo titun kan ti o rin sinu omi, lọ labẹ omi, ti o si jade wa lati inu omi, eyi yio mu ki a ri ohun ti Jesu ṣe lati gba wa la. Ìrìbọmi jẹ́ àpẹẹrẹ pípé ti iṣẹ́ ètùtù ti Kristi (1 Kọ́r. 15:1-4). Ohun gbogbo ti o nilo lati rin ni iṣẹgun lori ẹṣẹ ni a ti pese re. Fi ara rẹ silẹ loni Lati ma a gbe ninu iṣẹgun ti Kristi lailai.
BIBELI KIKA: 1 Kọ́r. 15:1-4
ADURA: Oluwa, mo pinu loni lati gbe igbe aye isegun ti Kristi ti gba fun mi.