LET GOD ARISE

THE SEED
“Let God arise, let his enemies be scattered: let them also that hate him flee before him.” Psalms 68:1

Let God arise. The word “let” is a powerful and action word. It involves your will, your choice, your decision. When you allow God to arise in your life, He will bring you a new season of favour, increase, and overflow. He will scatter the enemies that have come against you. But you need to rise up too. Rise up to worship the Lord and declare that He’s your Healer, Restorer, Provider and Peace. Even when everyone around you seems to be losing their minds, you can experience God’s supernatural peace and provision. God wants you to experience a great exchange today. He will give you beauty for your ashes, joy for your pain, victorious praise for your sadness and dancing for your mourning. Today is a day to claim God’s promise to lift up your valleys, straighten your crooked and rough places, and reveal His glory through your life (Isaiah 40:4-5). He can bring you from famine to abundance, from devastation to victory, only if you believe.

BIBLE READING: Isaiah 40:4-5

PRAYER: God arise and scatter all my enemies in Jesus name

                                                   

 KI OLORUN KI O DIDE

IRUGBIN NAA

“Ki Olorun ki o dide, ki a si tu awon ota re ka. Ki awon ti o korira re pelu, ki won ki o salo kuro niwaju re.” Saamu 68:1

Ki Olorun ki o dide. Oro yi je oro ti o lagbara ati oro ise. O nilo oun ti o yan ati ipinu re. Ti o ba gba Olorun laye lati dide ninu aye re, yio fun o ni  asiko titun fun ojurere, ati ekunrere Ibukun. Yio tu awon ota re ka ti won dide si o , sugbon iwo naa nilo lati dide. Dide lati sin Oluwa ki o si jewo wipe oun ni o mu o larada, oun ni olurapada re, olupese re ati alafia re.

Nigba ti awon to wa ni ayika re kuna lati ni ifokan  bale , iwo le ni iriri Alafia ati ipese Olorun. Olorun fe ki o ni iriri ayipada nla loni. Yio fun o ni ewa dipo eeru, ayo dipo inira, yio si so ikaanu re di ijo. Oni ni ojo lati gba gbogbo ileri Oluwa lati  gbe petele re soke, lati tun ona re se ati lati fi ogo re han nipase aye re (Isaiah 40 : 4-5)  O le mu o lati inu iyan wa sinu opolopo, lati inu idaamu wa sinu isegun, ti o ba gbagbo.

BIBELI KIKA: Isaiah 40 : 4-5

ADURA: Olorun dide, ki o si tu awon ota mi ka ni oruko Jesu. Amin.

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *