FULLNESS OF JOY

THE SEED
“Thou wilt shew me the path of life: in thy presence is fullness of joy; at thy right hand there are pleasures for evermore.” Psalms 16:11
 

We can be said to have fullness of joy in God if our joy in God is so full, that we know we have arrived at the end of our quest for satisfaction. In other words, there may be ups and downs in our level of satisfaction owing to sin or pain, but we never need to be in doubt that Christ is the end of our search. We will never leave this fountain to find a more satisfying one. Here is fullness. He is fullness. In today’s world, we have so many weak and defeated christians because we don’t have the joy of the Lord that gives us strength to go from day to day. When our circumstances are dark, and they are bad, we need that joy which comes from being in His presence, which comes from praising and worshipping Him, As we worship and praise the Lord, we come into His presence where there is fullness of joy, and the joy of the Lord gives us strength.

BIBLE READING: Psalms 16

PRAYER: My soul and body rejoice in you O Lord always and forever more Amen

 

                                                        EKUNRERE AYO

IRUGBIN NAA

“Iwo yio fi ipa ona iye han mi, ni iwaju re ni ekunrere ayo wa. Li owo otun re ni didun inu wa lailai.” Saamu 16:11

A le so wipe a ni ekunrere ayo ninu Olorun nigba ti ayo wa ba kun tobeege ti a mo wipe a ti de ebute itelorun.  Loro kan, a le ma ni itelorun to peye nitori ese tabi inira, sugbon ko ye ka siye meji wipe Kristi ni opin oun gbogbo ti a nwa. Ko si itelorun kan to ju eyi lo. Oun gangan ni ekunrere. Ni aye ode oni, opolopo Kristeni alailagbara lo wa nitori won ko ni ayo Olorun ti o nfun won ni agbara fun igbe aye ojoojumo. Nigba ti oun gbogbo ba sokukun, ti ko si dara, a nilo ayo ti o ma nwa nipa wiwa ni iwaju Olorun, nipa fifi iyin ati ope fun. Bi a se nfi ope ati iyin fun Olorun, a nwa si iwaju re ni ibi ti ekunrere ayo gbe wa, ayo olorun si ma nfun wa ni agbara.

BIBELI KIKA: Saamu 16

ADURA: Okan mi ati ara mi nyo ninu re Oluwa nigbagbogbo ati titi lai, Amin.

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *