THE SEED
“But it shall not be so among you: but whosoever will be great among you, let him be your Minister; And whosoever will be chief among you, let him be your servant” Matthew 20:26-27
To be great means to be outstanding in whatever one does. It means to be successful, prosperous. But the greatest definition for the word greatness is, ‘a life of blessing’ and any man that is great is a man whose life is blessing people everyday. A man that gives joy and succour to others. In the opening Scripture, to Jesus Christ, true human greatness then came down to this: humble servanthood. Putting the needs of others ahead of your own for your whole life, and whoever was most willing to lay himself down for the good of others would be called greatest in the Kingdom of Heaven. Remember that when you talk about your own greatness, it’s easy to forget that we are saved by grace alone and so Jesus says greatness in the kingdom is earned by servanthood. Humble yourself now, stop living for yourself, stop living for your earthly advantages, your earthly pleasures, earthly prestige and power and glory. Greatness through God-sized dreams are made possible when faithfulness connects with fruitfulness. The pursuit of greatness is an invitation to explore how the depth and intensity of following Jesus Christ can result into a spirituality of relevancy and restoration, vitality and transformation, victory and liberation.
BIBLE READING: Matthew 20:26
PRAYER: Heaven is my greatest goal in life
OHUN TI O KOJA GIGA
IRUGBIN NAA
“Sugbon ki yio ri be ni arin yin, sugbon enikeni ti o ba fe po ninu yin, e je ki o se iranse yin” Matteu 20:26
Lati je eni giga tumo si wipe ki eniyan maa tayo ninu oun gbogbo ti o ba nse. O tumo si wipe ki eniyan se aseyori, ki o si se rere. Sugbon itumo ti o ga ju ni ‘igbe aye ibukun’. Eni ti o ba ga ni eni ti aye re n bukun fun awon eniyan lojoojumo. Eni ti o fun elomiran ni ayo ati idunu . ninu eko kika tio saaju, a ri Jesu Kristi gege bi eni ti o ga , ti o si tun je ojise onirele. O gbe aini awon elomiran bori tire fun gbogbo igbesi aye re, eni ti o setan lati fi ara re sile fun anfani awon miran, oun ni a o pe ni eni ti o gaju ninu ijoba Olorun. Ranti wipe bi o ba nsoro nipa giga ara re, o rorun lati gbagbe wipe oore ofe la fi ri igbala, torina, Jesu so wipe , eni ti o ba ma ga ninu ijoba Olorun, yio koko di iranse.
Re ara re sile bayi, mase gbe igbe aye ara re nikan, mase gbe igbe aye fun ere ti aye nikan, awon adun aye, ipo ati agbara aye ati ogo. Giga nipase imo Olorun seese nigbati isotito ba papo mo iso- eso.
Ninu ona lati ga, a pe wa lati ri bi titele Jesu Christi se le yori si ayipada rere ti emi, isegun ati ominira.
BIBELI KIKA: Matteu 20:26
ADURA: Orun je ilepa mi ti o ga ju laye