DESIRES AND WORLDLINESS

THE SEED
“Jesus Christ the same yesterday, and to day, and for ever.” Hebrews 13:8

The solution to both desires and worldliness is this: Jesus can and does respond differently to our different circumstances. But now we see that not only are those responses rooted in a consistent character of love and wisdom and righteousness and power, but also in a perfect knowledge and plan so that he never changes his mind because of unforeseen circumstances. He is the same in His perfect foreknowledge, perfect plan and perfect execution of that plan in all the details of your life to bring about the glorious goal for all His children. His love is the same; righteousness is the same; wisdom is the same and so is his power. And He is not bound by the limitations of finite man, so that he could ever be surprised by any of your circumstances. If Christ could be trusted once to be the helper of those who refused to love money and were content with what they had, then he can be trusted today and tomorrow also for every generation of Christian under any financial circumstance.

BIBLE READING: Hebrews 13

PRAYER: Heavenly Father remove every desiring spirit toward the things of the world in my life

 

   IFE OKAN ATI IFEKUFE AYE

IRUGBIN NAA

“Jesu Kristi, okan lana, loni ati titi aye.” Heberu 13:8

Ona abayo si ife okan ati ifekufe aye ni eyi: Jesu le dahun, o si maa ndahun ni orisirisi ona si orisirisi isele ninu aye wa. Sugbon nissisiyi, a ri wipe kii se pe awon idahun yii je iwa ife ni igba gbogbo, ati ogbon ati ododo ati agbara nikan, sugbon, ninu imo ti o peye ati ero, ki On ma baa yi okan Re pada nitori awon isele airotele. O wa sibe sibe ninu imotele re ti o pe ati ero re ti o peye ati bi o ti n mu ero Re se daradara ninu aye re lati mu afojusun re ti o logo se ninu aye gbogbo omo Re. Ife re wa bakan naa sibe, ododo re wa sibe, ogbon re wa sibe, agbara re wa sibe. Isoro eniyan ko le daa duro to bee ti ko si isele ti o le yaa lenu. Bi won ba le gbekele Kristi nigbakanri wipe On ni oluranlowo awon ti kii se olufe owo, ti won si ni itelorun pelu ohun ti nse tiwon, bakan naa, a tun le gbekele loni ati lola, fun gbogbo iran Kristeni lori eto isuna.

BIBELI KIKA: Heberu 13

ADURA: Baba mi orun, mu gbogbo emi ti nse ife ohun ti aye kuro ninu aye mi. Amin

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *