ALL THINGS FOR US

THE SEED
But rather seek ye the kingdom of God; and all these things shall be added unto you.” Luke 12:31

All things are for you and me as opposed to against us. Christ owns and has taken possession of us. We can look people and situations in the face and say, “You may mean this for evil but my Father has designed it for my good. Do what you will.” Each Christian can face evil tidings with the same calmness and assurance that we see in Christ. Each of us has the right and warrant to say, “Do as you will, I will keep on working for the Lord. You cannot overthrow God’s plan for me.” Dearly beloved, God has a will and purpose for each of us and until that is complete we are invincible. Until we breath our last, we must continue serving our Lord. We must continue using all the means of grace through which God gives us everything pertaining to life and Godliness. We needn’t be overly anxious about health, family, money, country or plans. For all these things, whatever form they take, are for us by divine design. In the midst of it all, we will remain safe.

BIBLE READING: Luke 12

PRAYER: Let the focus of your Kingdom be my priority O Lord

 

   OUN GBOGBO FUN WA

IRUGBIN NAA

“Sugbon, e ma wa ijoba Olorun, gbogbo nkan wonyi ni a o fi kun fun yin.” Luku 12 :31

Oun gbogbo je fun iwo ati emi, won ko lodi si wa. Olorun lo ni wa. A le wo awon eniyan loju ki a si so wipe, oun ti won ro fun ibi, Olorun mi yiipada si rere fun mi, e se oun te fe se.

Gbogbo kristeni ni o le dojuko  akoko ibi, pelu ifarabale ati idaniloju ti a ri ninu Jesu Kristi. Gbogbo wa ni a ni eto lati so wipe ‘ e se oun ti ba fe se, ngo maa sise lo fun Oluwa, E o le da eto Olorun fun mi nu’. Ara, Olorun ni ife ati eto fun enikan kan wa, ko si  eni ti o le bori re, titi yio fi wa si imuse.

Titi aye wa ni a ani lati maa sin Olorun. A nilo lati maa fi  oore-ofe ti ri nipase Olorun fi gbe igbe aye iwa mimo. Ko ye ki a maa se aniyan fun ounkoun, nitori fun gbogbo awon nkan wonyi, ni onakona toba gba, o je tiwa nipa eto lati orun wa. Ninu gbogbo re, a o wa ni ailewu.

BIBELI KIKA: Luke 12

ADURA: Oluwa, jeki ijoba re se pataki fun mi . Amin

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *