THE LAW OF LOVE

THE SEED
If ye fulfill the royal law according to the scripture, Thou shalt love thy neighbour as thyself, ye do well:” James 2:8

Christ’s law of love, which is to be a reality in our lives by demonstrating it to other people. Love can’t remain passive. It explodes outwardly, reaching out to everyone without favoritism. When this happens, we know it has become the guiding principle in our lives. It does not leave us in a good place to not have love for others or concern for the lost. We must never forget that the “Law of Love” demands that we seek the best for our neighbour and that is their salvation. We are instructed to mimic our Saviour by walking in love towards all. Our knowledge was never intended to destroy compassion, tenderness, concern or love for the persons and souls of men and women. Jesus had more knowledge than we will ever have. He knew and had determined who would and would not be saved. Still He preached to them all and wept over those who would not believe.

BIBLE READING: James 2

PRAYER: Deposit in me your true love O Lord

 

OFIN TI IFE

IRUGBIN NAA

“Sugbon bi enyin ban mu ofin ni se gege bi iwe-mimo, eyi ni , iwo fe enikeji re bi ara re, enyin nse daradara.”   Jakobu 2:8

Ofin ife ti Kristi, eyi ti n di mimuse ninu aye wa nigba ti a ba fife han si omonikeji, ife kii tutu, a maa yo jade, yio si maa de odo olukuluku eniyan laise oju isaju. Nigba ti eleyi ba nsele, a mo wipe o ti di ohun ti n se amona aye wa. A ko gbodo ni iwa aibikita tabi wu iwa alani ife tabi itara fun awon ti o ti sako lo. A ko gbodo gbagbe pe ofin ti ife wipe ki a maa wa rere omonikeji wa, eyi ti n se igbala won. A paa lase fun wa wipe ki a wuwa bii ti Olugbala wa nipa ririn ninu ife si gbogbo eniyan. Ogbon ti a ni, kii se lati fi ba aanu, ipamora, itara tabi ife fun okunrin ati obinrin je. Jesu ni ogbon ju eyi ti eniyan le ni. O mo, osi ti pinnu eni ti yio ri igbala ati eni ti ki yio ri igbala. Sibe, O waasu fun gbogbo won, o si sokun nitori awon ti ki yio gbagbo.

BIBELI KIKA: Jakobu 2

ADURA: Fi ife otito re sinu mi, Oluwa. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *