A SPIRIT OF PRAISE

THE SEED
“Because thy lovingkindness is better than life, my lips shall praise thee.” Psalms 63:3

When we develop a spirit of praise and praise Him, God reveals Himself to us. As we praise Him as Creator and King of this world, we admit and recognize that we are not in control, but He is. He is above all. Evil will not stick around if we are praising our God, who will fight our battles for us. Sometimes even within our prayers, we can tend to complain about our problems. God knows our hearts and He cares about all that concerns us. But through praise, we are focused on Him, no longer allowing too much attention to be centred around the struggles. We are reminded of what He has already done in our lives. We are reminded that He knows what concerns us and is capable of taking care of all that burdens us. If you are having difficulty praying, begin to praise and you’ll have an ocean to swim in. Through a heart of praise, we realize that God doesn’t just change our situations and work through our problems, He changes our hearts.

BIBLE READING: Psalms 63

PRAYER: Put on me the garment of Praise O Lord

 EMI IYIN

IRUGBIN NAA

“Nitoriti iseun ife re san ju iye lo, ete mi yio maa yin o.” Orin Dafidi 63: 3

 

Nigba ti a ba ni emi iyin ti a si yin in, Olorun a fi ara re han wa. Bi a ti n yin in gege bi eleda ati oba aye yii, a mo, asi gba wipe awa ko si ni akoso, bikose on. O ju ohun gbogbo lo. Ohun ibi kan ko lee se wa nigba ti a ba n yin in, eni ti yio gba ija wa ja. Nigba miran, ninu adura wa, a maa n kun nipa awon isoro wa. Olorun mo okan wa, o si n bojuto ohun gbogbo ti n se tiwa. Nipase iyin, a koju si ohun nikan, a ki yoo si je ki okan wa ki o wa lara awon ilakaka tabi isoro wa. E je ki a ranti ohun ti o ti se ninu aye wa, ki a si ranti wipe O mo ohun ti n se tiwa, o si le se ohun gbogbo ti n dun wa lokan. Bi adura gbigba ba nsoro fun o, bere si ni yin in, iwo yio si ni ekunrere ibukun.. Nipase okan iyin, ari wipe Olorun kii yi aye wa pada nikan, o n yi okan wa pada pelu.

BIBELI KIKA: Orin Dafidi  63

ADURA: Gbe aso iyin wo mi, Oluwa. Amin

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *