THE MERCIFUL GOD

THE SEED

“It is of the LORD’S mercies that we are not consumed, because his compassions fail not.” Lamentations 3:22

We need to share the good news of God’s Mercy with the guilty, convicted, desperate lives that have only heard judgment, wrath, and condemnation. That is our good news. It’s not a mystery to the Lord that you are tired in your waiting. It’s not a mystery to Him that you are tired in your darkness and in your struggle with life’s battle. But He is with you. He is keeping you and looking after you. When  you hear God is compassionate and merciful, sometimes it doesn’t resonate. For you to experience that the Lord is compassionate and merciful, like Job, you must go through the waiting period and only through this experience of waiting, could Job come to see God for who He is – that He is a God who is compassionate and merciful.

BIBLE READING: Lamentations 3

PRAYER: Heavenly Father, show me your mercy in this month

 

 OLORUN ALAANU

IRUGBIN NAA

“Aanu Oluwa ni, ti awa ko fi parun tan, nitori ironu aanu re ko li opin.” Ekun Jeremiah 3:22

 

A ni lati mu ihin ayo ti aanu Olorun to awon eni idalebi, awon ti a ti dalejo, awon eni ti ngbo idajo, ibinu ati idanilebi. Ihin ayo wa ni eleyi. Kii se ohun ti o pamo loju oluwa ni wipe o tile ti n sun o bee si ni, o mo wipe okunkun ati idamu aye re ti sun o sugbon o wa pelu re, o n toju re o si n boju to o. Nigbati o ba n gbo wipe alaanu ati oniyonu ni Olorun, nigba miran, kii ye ni, nigba miran, kii de inu okan re. O n gbo wipe alaanu ati oniyonu ni Olorun sugbon ko ka o lara. Ki o to le ni iriri wipe alaanu ati oniyonu ni Olorun, bii ti Jobu, o gbodo la igba iponju koja. Igba iponju yii ni Jobu ri Olorun ninu ewa re wipe O je Olorun ti o ni aanu ati iyonu.

BIBELI KIKA: Ekun Jeremiah 3

ADURA: Baba mi orun, fi aanu re han fun mi ninu osu yii, Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *