A CALL TO REPENTANCE 

THE SEED
If thou wilt return, O Israel, saith the LORD, return unto me: and if thou wilt put away thine abominations out of my sight, then shalt thou not remove. Jeremiah 4: 1(KJV)

The only way and the surest key to Eternal life is repentance, without this, there is no Salvation. Behold the Kingdom of God is very near,  closer to us than before. This is the time we should search our hearts if we are still with our creator or not, this is the time we should check our ways if it’s still on the same page with God our Father, this is not the time to toy with our Eternal home, No procrastination anymore,  this is the time to put enough oil into our lamp, this is the time to awake from our slumber,  for Jesus said: “The time is fulfilled and the Kingdom of God is at hand, Repent ye, and believe the Gospel”. The Gospel of Jesus Christ regarding sin, forgiveness and Holiness, is a zero tolerance to No repentance, No Salvation and No Eternal life. Brethren, it is possible you have lost your Salvation or you have not known Jesus at all. I am assuring you today, the door is still open for you to go back to the Lord for genuine repentance and forgiveness so that you can be counted among those that have their Names written in the book of life because if your Name is not found there,  it is Eternal damnation, which I pray will not be our portion in Jesus Mighty Name. He that hath an ear, let him hear what the Spirit is saying unto the churches.

BIBLE READINGS:  Revelation 3: 19 –  22

PRAYER: My Father I cling unto you, hold me tightly with thy right hand till Eternity in the Name of Jesus.Amen

 

ÌPÈ FÚN ÌRÒNÚPÌWÀDÀ

IRUGBIN NAA

Israeli bi ìwọ o bá yipada, li Olùwà wí, yipada sọ́dọ̀ mi; àti bí ìwọ o ba mú ìríra rẹ kúrò níwájú mì, ìwọ kì o sí rìn kiri. Jeremáyà 4:1

Ọna kansoso ati kọ́kọ́rọ́ to daju fun iye ainipekun ni ironupiwada, laisi eyi ko si igbala. Kíyèsí i, ijoba Ọlọ́run ti sùnmọ̀ tòsí wa gan-an ju tí àtẹ̀hin wá lọ. Àsìkò yi ni o yẹ ki a ma a yẹ ọkàn wa wo, ti a ba wa pẹ̀lú Ẹlẹ́dá wa tabi bẹẹ kọ. Ni akoko yi ni o yẹ ki a ṣayẹwo awọn ọna wa ti o ba wà, ni oju-ewe kanna pẹlu Ọlọrun baba wa; eyi kii ṣe akoko lati ṣe ere pẹlu ile ayeraye wa. Kò si aye fún sísun ọjọ́ ìgbàlà di ọlá mọ,  eyi ni akoko ti a lè fi epo ti o to sinu àtùpà wa, eyi ni akoko  lati ji kúrò lójú orun wa, nitori Jesu wipe “Akoko naa ti pe, ati pe ijọba Ọlọrun ti sunmọ etile “Ẹ ronupiwada, ẹ gba ihinrere gbọ́”. ninu ijọba Jesu Kristi nipa tí ẹ̀ṣẹ̀, idariji ati iwa mimọ, ai bìkítà fún ìrònúpìwàdà, igbala, ati ai si iye ainipẹkun. Ará kùnrin  o ṣe e ṣe ki o ti sọ igbala rẹ nu, tabi o ko tii mọ Jesu rara. Mo n fi da yin loju loni, ilẹ̀kùn si ṣì silẹ wa fun yin lati pada sọ́dọ̀ Oluwa fun ironupiwada tootọ ati idariji. Kí a ba le ka ọ mọ́ àwọn ti wọ́n kọ orúkọ wọ́n sinu ìwé ìyè, nitori ti a ko ba ri orukọ rẹ nibẹ, èyí yíò jẹ ijiya  ayeraye, ti mo gbadura, ki yíò jẹ ipin wa ni orukọ nla Jésù. Ẹnití o ni eti jẹ ki wọn gbọ ohun ti ẹmi n sọ fun awọn ijọ.

BIBELI KIKA: Ifihan 3:19-22

ADURA:  Baba mi mo di mọ́ Ọ, di mí mú ṣinṣin pẹ̀lú ọwọ́ ọtun Rẹ titi ayeraye lórúkọ Jesu Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *