THE SEED
“Ye are my friends, if ye do whatsoever I command you.” John 15:14 (KJV)
What a great love Jesus showed to humanity by elevating us from servanthood (John 15:15) into friendship with Him. Approval into this bond is determined by obedience to Hiscommands. Love unites all relationships, and we all tend as humans to want to satisfy the people we love. Likewise, If we love Jesus, we have to walk in His ways. Every time we are about to deviate from His will, the Holy Spirit within us quickens our hearts. Remember that friendship with the world is an enmity with God. Commit your heart to His will and have your friendship sealed with Jesus
BIBLE READINGS: John 15:9-17
PRAYER: Jesus, help me to love you more and remain your friend forever. Amen.
IFE TI O NI GBENDEKE
IRUGBIN NAA
“Ọ̀rẹ́miniẹ̀yinńṣe,bíẹbáṣeohuntíèmi pàṣẹ fún yín.” — Johanu 15:14
Iru ife ti Jesu fi han awa eniyan nipa mimu wakuroninuipoeṛútiosisowadiòṛẹ́Reti pò ̣to! Ohun ti o gba wa sinu irepo yii naa ni igboran si àsẹ ̣Re.
Ife ni o so gbogbo ibasepo po, ati gege bi eniyan, a máa n fe lati té ̣ awon ti a feran lorun. Bakan naa, ti awa ba fe Jesu, a ni lati rin ni ona Re. Gbogbo igba ti a ba si fé ̣yè kuro ninu ife Re, Emi Mimo ti o wa ni okan wa yio ta wa ji. Ranti wipe ibare aye, isota Olorun ni. Fi okan re fun ife Re loni, ki a si fi edidi di irepo re pelu Re.
BIBELIKIKA:Johanu15:9-17
ADURA : Jesu, ran mi lowo lati le feran Re si, kii si je ore Re tit