THE SEED
”…but as He who called you is holy, you also be holy in all your conduct, because it is written, “Be holy, for I am holy.” I Peter 1:15-16 NKJV
Sanctification is not a one-time event; it’s a lifelong journey. It’s about living a holy and obedient life before God. As we walk with Him daily in obedience, we grow in holiness. Living a holy life involves both separation from participating in evil and being influenced by evil. We have to make constant conscious efforts to separate ourselves from participating in evil through our character or relationship. It’s a popular saying that some things are easier said than done. This is true in the sense that most Christians know what evil is and understand that our faith in Christ does not permit us to get involved in doing evil, but when we come across evil in the form of challenge or temptation, some children of God loses the knowledge and are overwhelmed by the pressure of evil that they easily compromise their faith. The knowledge we acquire in the word of God should give us the understanding that if we expose ourselves to peer pressure or evil company or take an interest in worldly sinful practices we would be exposing ourselves to compromise with evil. So the safest thing to do to keep walking with God in Holiness is to apply discipline. Whatever you want to do or say that entails evil, discipline yourself not to do it and you would have saved your Holy walk with God from corruption.
BIBLE READINGS: 1Peter 1:13-19
PRAYER: Lord make me and keep me, Holy, now and forever in your presence. Amen
IRIN MIMO
IRUGBIN NAA
“Ṣùgbon gege bí ẹni tí ó pè yín ti je mímo, ẹ̀yin pẹ̀lú sì je mímo nínú gbogbo ìwà yín, nítorí a ti kọ o pé, “Ẹ jemímo, nítorí èmi je mímo.” 1 Pétérù 1:15-16
Ìsọdimímo kì í ṣe ìṣẹ̀lẹ̀ kan ṣoṣo; o jẹ irin-ajo igbesi aye. O jẹ nipa gbigbe igbe aye mimọ ati igboran niwaju Ọlọrun. Bi a ti nrin pelu Re lojoojumo ninu igboran, a ndagba ninu iwa mimo. Gbígbé ìgbé ayé mímo je ìyàsotọ̀ kúrò nínú kíkópa nínú ibi àti kíkópa nínú ìwà ibi. A ni lati ṣe awọn igbiyanju mimọ nigbagbogbo lati ya ara wa kuro ninu kikopa ninu ibi nipasẹ iwa tabi ibasepo wa. O jẹ ọrọ ti o gbajumọ pe o dun so ju Lati se. Èyí je òtíto nítoripé ọ̀pọ̀ àwọn Kristẹni mọ ohun tí ibi je, won sì lóye pé ìgbàgbo wa nínú Kristi kò jeká lowo nínú ṣíṣe ibi, ṣùgbon nígbà tí a bá pàdé ibi nínu ipenija tàbí adanwo, opo ọmọ Ọlorun pàdánù imo, won a si jekí ibi ki o bori won debi wipe won yio ko igbagbọ wọn. Ìmọ̀ tí a ní nínú Ọ̀rọ̀ Ọlorun gbodọ̀ fún wa ní òye pé bí a bá jekí ẹgbe búburú ki o gba okan wa ninu iwa buburu ẹ̀ṣẹ̀ ti ayé, yio rorun fun wa lati wuwa ibi. Nitorinaa ohun ti o ni aabo julọ lati ṣe ni lati tẹsiwaju pẹlu Ọlọrun ninu Iwa mimọ pelú isera eni. Ohunkohun ti o ba fẹ lati ṣe tabi sọ ti o je ti ibi, ba ararẹ wi lati ma ṣe ati pe iwọ yoo ti gba irin-ajo mimọ rẹ pẹlu Ọlọrun lọwọ ibajẹ. Gẹgẹbi iyanju
BIBELI KIKA: 1 Pétérù 1:13-19
ADURA: Baba orun,Mimo l‘oruko re at‘ise Re, Mo nfe rin ninu mimo pelu re, Oluwa tumise, ki o si so mi di mimo, nisiyi ati laelae niwaju Re. Amin.