THE SEED
“Not that we are sufficient of ourselves to think any thing as of ourselves but our sufficiency is in God.” 2 Corinthians 3 : 5
In the scripture above, apostle Paul makes it known that we are not sufficient of ourselves, so no man can think of his ability or adequacy but God. God is sufficient in power; God hath spoken once, twice have I heard that power belong unto God. (Psalm 62 :11) when He introduced Himself in (Revelation 1:8), Almighty and He gives power, also (Luke 10:19, John 1:12, John 10:18) and more. God is sufficient in wisdom; That their hearts might be comforted, being knit together in love and unto all riches of the full assurance of understanding to the mystery of God, and the Father, and of Christ, In whom are hid all the treasures of wisdom and knowledge. Colossians 2:2-3. The wisdom and knowledge that the world needs is hidden in God. He gives it liberally, (James 1:5) and God gave Solomon, He can give you too. (1 Kings 4:29). God is sufficient in strength; And Moses said unto the people, remember this day, Which ye came out from Egypt, out of the house of bondage; for by strength of hand the Lord brought you out from this place; (Exodus 13:3), what problem are you in? God has the strength and ability to take you out and also He gives strength to them that have no might. (Isaiah 40:29). If any man rely on his natural ability before God it amounts to pride. Beloved, empty yourself before God so that He can empower you out of His sufficiency.
BIBLE READING: Isaiah 40 : 29 – 31
PRAYER: Father empower me for your glory
ỌLỌRUN TI O TÓ NÍNÚ OHUNGBOGBO
IRUGBIN NAA
“Ki iṣe pe awa tó fún ara wa lati ṣírò ohun kohun bí ẹnipe lati ọdọ àwa tikarawa ; ṣugbọn latí ọdọ Ọlọrun ní tito wà.” 2 Kọrinti 3:5
Nínú ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó wà lókè, àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù jẹ́ ká mọ̀ pé a kò tó fún ara wa, nítorí náà, kò sẹ́ni tó lè ronú nípa agbára tàbí tito fún ara rẹ̀, bí kò ṣe nipasẹ Ọlọ́run. Ọlọrun Pe, ni ti to nínú agbara; Olorun ti sọrọ lẹẹkan, lẹẹmeji ni mo ti gbọ pe agbara jẹ ti Ọlọrun. Orin Dafidi 62:11, nigba ti O fi ara rẹ han ninu ifihan 1:8, Olodumare si fun ni ni agbara pẹlu Luku 10:19, Johannu 1:12, Johannu 10:18 ati diẹ sii. Ọlọrun pọ to nínú ọgbọn; Kí wọ́n lè ní ìtùnú nínú ọkàn, kí wọ́n sì so wọ́n pọ̀, láti kójọ nínú ìfẹ́ àti ní tí gbogbo ọrọ̀ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìdánilójú òye, sí ohun ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run àti baba, àti ti Krístì. Nínú ẹni tí a fi gbogbo ìṣúra ọgbọ́n àti ìmọ̀ pamọ́ sí. Kólósè 2:2-3. Ọgbọ́n àti ìmọ̀ tí ayé ní fún lílò, ti fara sin nínú Ọlọ́run. Ó fúnni ní ọ̀pọ̀ yanturu ọgbọn àti ìmọ. Jakọbu 1:5. Bi Ọlọ́run tì fi fún Sólómọ́nì, ó sì lè fún ọ pẹ̀lú 1 Ọba 4:29. Ọlọrun to ni agbara; Mose si wi fun awọn enia na pe, Ẹ ranti ọjọ oni, ni ti ọdun ti ẹ ti Egipti jade wá, kuro ni ilẹ oko-ẹrú; Eksodu 13:3, iṣoro wo ni o wa ninu rẹ? Ọlọ́run ní okun àti agbára láti mú ọ jáde, àti pẹ̀lú ó fi agbára fún àwọn tí kò ní agbára, Isaiah 40:29. Bí ẹnikẹ́ni bá gbẹ́kẹ̀lé agbára tí ara rẹ̀ níwájú Ọlọ́run, èyí yíò jẹ́ ìgbéraga. Olufẹ, tú ara rẹ̀ palẹ niwaju Ọlọrun, ki O bá a le fun ọ ni agbara ninu ti to Rẹ
BIBELI KIKA: Aísáyà 40:29-31
ADURA: Baba fun mi ni agbara fun ogo rẹ ni orúkọ Jesu amin.