Amazing Peace

THE SEED
“Thou wilt keep him in perfect peace, whose mind is stayed on thee: because he trusteth in thee.” Isaiah 26:3

Amazing harmony is a state of independence from disturbance inside the spirit; it is wonderful peace ruling inside. Today, we are encircled by much depression and gloom and continually undermined with trial, disillusion, fear and disappointment. Wonderful peace – a peace in our souls that is established by the Prince of Peace; a genuine peace both internally with God and apparently toward all men, even people who think about us as their foe. A misleading peace is effortlessly broken by each misunderstanding, however with an unshakable peace, no power on earth can shake. We find a harmony that is consistent, unfaltering, and never-ending for we realize that our God has everything taken care of and regardless of how terrible this world can get we realize that He has perfectly cleared a path for us to avoid getting overwhelmed. Dear beloved, perfect peace doesn’t imply that you won’t face trials, tests, abuses and perhaps demise for your declaration in Christ. It intends that among everything, and through everything, you will enjoy a peace in your heart that will allow you to confront those things regardless, and still come out as a victor through the power of God.

PRAYER
Lord God Almighty I plead for your peace, the peace that will make me overcome every trial and test of faith in Jesus name Amen

BIBLE READINGS: Philippians 4: 4-9

ALAFIA AGBAYANU
IRÚGBÌN NÁÀ
“Iwọ o pa a mọ́ li alafia pipé, ẹniti ọkàn rẹ̀ simi le ọ: nitoriti o gbẹkẹle ọ. Isaiah 26:3

Agbayanu irẹpọ jẹ ipo ominira kuro ninu idamu ninu ẹmi; o jẹ ìyanu ti alaafia njoba ninu rẹ. Loni imi-ẹ̀dun yika wa pẹlu ìbànújẹ pupọ ati òkunkun; ati nigbagbogbo ni a sì nni idanwo, pẹlu rudurudu, ìbẹrù ati ibanujẹ. Iyanu alaafia – Eyi ni àlàáfíà kan, ninu ọkan wa ti a fi idi rẹ mulẹ nipasẹ ọmọ-alade alafia; èyí sì tún jẹ́ alàáfíà tòótọ́ nínú Ọlọ́run àti sí gbogbo èèyàn, àní àwọn
èèyàn tí wọ́ n rò pé a jẹ́ ọ̀tá wọn. Alaafia tí o ní iṣina ninu, ní a fọ tutù la i lo agbára pẹlu oye, sibẹsibẹ alaafia ti ko ṣe e mi yi, ní ko si agbara lori ilẹ aye tí o le e mìi. A rí ìrẹ́pọ̀ kan tí kì í yẹ̀, tí kò sì lópin, nítorí a mọ̀ pé Ọlọ́run wa, ní ohun gbogbo ti o sì nṣe abójútó wọ́ n, àti láìka bí ayé yìí ṣe lè burú tó. A mọ̀ pé ó ti tún ọ̀ nà kan ṣe ní pípé pérépéré fún wa láti yẹra fún ki irẹ̀wẹ̀sì bori wa. Olùfẹ́ ọ̀ wọ́ n alaafia pipe kò túmọ̀ sí pé ẹ kò ní ni idojúkọ́ , àwọn àdánwò, ìdánwò, eebu, àti bóyá ìparun fún ìkéde yín nínú Krístì. O pinnu pe laarin ohun gbogbo ati nipasẹ ohun gbogbo iwọ yoo gbadun alaafia ninu ọkan rẹ ti yoo jẹ ki o k’oju awọn nkan wọnni laibikita; lẹhin eyi iwọ yíó sí tun jade bi aṣẹgun nipasẹ agbara Ọlọrun.

ADURA
Oluwa Ọlọrun Olodumare mo bẹbẹ fun alaafia rẹ, alaafia ti yoo mu mi bori gbogbo idanwo ati adanwo ìgbàgbọ ni orúkọ Jesu amin.

BIBELI KIKA: Filipi 4: 4-9

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *