ARE YOU ROOTED IN CHRIST AS TAUGHT?

THE SEED

”So then, just as you received Christ Jesus as Lord, continue to live your lives in him, rooted and built up in him, strengthened in the faith as you were taught, and overflowing with thankfulness. Colossians 2:6-7 NIV

These verses illustrate the importance of being rooted in Christ, a foundation that sustains us and allows us to flourish in our Christian journey. Being rooted in Christ is likened to a tree planted by the river’s side according to the book of Psalm 1. Being rooted in Christ comes with the confidence to not have fear of any challenge of life because you are rooted in the right place that can sustain you through all odds of life. Also, in the Psalm we see the relationship between delighting in God’s Word and being firmly rooted, leading to a life marked by fruitfulness and prosperity.

Moreover, to be rooted in Christ is to be grounded in love which is foundational to our Christian walk. This enables us to extend kindness and compassion to others as we walk in the footsteps of our Lord. Beloved, as we reflect on being rooted in Christ, let us be intentional in our spiritual practices. Delighting in God’s Word, walking in love, and trusting in the Lord contribute to a deep and solid foundation. Like a well-nourished tree, we can withstand the trials of life and bear fruit that glorifies our Heavenly Father.

BIBLE READINGS:  Psalm 1: 1-3

PRAYER: As I remain rooted in Christ, Lord let me abide in your Word, and be filled with love, and unwavering trust in you.  Amen.

 

ǸJẸ́ O GBILẸ NÍNÚ KRISTI BÍ ÀTI ṢÉ KỌ́ Ọ

IRUGBIN NAA

“Nítorí náà bi ẹ̀yin tí gba Kristi Jésù Olúwa, bẹẹni ki ẹ máa rín nínú Rẹ̀. Kì ẹ fí gbongbo múlẹ̀, kí a sì gbé yín ró nínú rẹ̀, kí ẹ sí fi ẹsẹ múlẹ̀ nínú igbagbọ yin, gẹ́gẹ́ bí a tí kọ yín, kí ẹ sí máa pọ nínú rẹ̀ pẹ̀lú Idúpẹ́”. Kólósè 2:6-7

Àwọn ẹsẹ wọ̀nyí nṣàkàwé Ìjẹ́ pàtàkì fífi ìdí múlẹ̀ nínú Kristi, ìpìlẹ̀ kan tí o ńgbé wa ró tí ó sì ńjẹ́ kí a gbinlẹ̀ nínú ìrìn àjò Kristẹni. Ifidimulẹ ninu Kristi ni a fi wé igi ti a gbin si ẹba odo gẹgẹ bi Iwe Orin Dafidi ori kíni. Láti fi ìdì múlẹ̀ nínú Kristi wá pẹlu igboiya lati ma jẹ́kí a bẹru eyikeyi nínú àwọn ipenija nínú igbesi aye wa, nitori pe o ti fi di múlẹ̀ ni aaye ti o tọ ti o le gbe ọ duro,  nipasẹ gbogbo awọn wàhálà inú aye. Pẹ̀lúpẹ̀lù nínú Sáàmù, orí kíni, a rí àjọṣe tó wà láàárín ṣíṣe inú dídùn sí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run àti títa gbòǹgbò mọlẹ nínú ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, tí o yọrí sí gbígbé ìgbésí ayé tí o ni   èso àti àṣeyọrí.  Jubẹlọ, lati wa ni ifi idi múlẹ̀ ninu Kristi jẹ, wi wa ninu ifẹ ti o jinlẹ nínú ìrìnàjò Kristẹni wa.  Èyí máa ń jẹ́ kí a lè fi inú rere àti ìyọ́nú hàn sí àwọn ẹlòmíràn, bí a ṣe ń rìn ní àwọn ọ̀nà ti Olúwa nrin.  Olufẹ bi a ṣe n ronu lori fifi ìdìmú lẹ ninu Kristi, ẹ jẹ ki awọn iṣe ti ẹmi jẹ wá lọ́kàn.  Níní inú dídùn sí àwọn ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, rí rìn nínú ìfẹ́ àti gbígbẹ́kẹ̀lé Olúwa, ńṣè irànwọ́ sí  íjinlẹ̀ tí ó sì fẹsẹ̀ múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí igi tí a fún, ni àwọn èròjà  láti dàgbà dáradára, a lè fara da àwọn àdánwò ìgbésí-ayé, kí a sì so èso tí ń fi ògo fún Baba wa Ọ̀run.

BIBELI KIKA: Orin Dafidi 1:1-3

ADURA: Bi mo ti fidi múlẹ̀ ninu Kristi, Oluwa jẹ́ ki n gbe inu ọ̀rọ̀ Rẹ̀ ki n si kun fun ìfẹ́ ati igbekele ti ko ni àyídáyidà. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *