THE SEED
“Immediately the fountain of her blood was dried up, and she felt in her body that she was healed of the affliction.” Mark 5: 29 NKJV
Jesus was ‘pressed’ on every side. He was in the midst of a great crowd of people, in all His power and glory. But only this woman ‘touched’ and drew power from Him. In that touch of faith was enough power to immediately and permanently destroy an affliction she had carried for several years. Isn’t that amazing? Similarly, there are crowds of people in the church today, having a nice time and getting entertained. But many never ’touch’ the Lord and encounter Him. Are you one of the few?
PRAYER
Heavenly Father I want to continually encounter Your Power, Your Wisdom and Your Grace, in Jesus’ name. Amen.
BIBLE READINGS: Mark 5:24-30
SE IWO NAA FOWO KAN JESU BII
IRUGBIN NAA
“Lẹsẹkẹsẹ isun ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ gbẹ, ó sì nímọ̀lára ninu ara rẹ̀ pe a ti mu oun láradá ninu ìponjú.” Máàkù 5:29 KJV
A ‘tẹ Jesu’ niha gbogbo. Ó wà láàrín ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn, nínú gbogbo agbára àti ògo Rẹ̀. Ṣugbọn obinrin yi nikan ni o 'fọwọkan’ O si fa agbara lati ọdọ Rẹ. Nínú ìfọwokan naa pelu ìgbàgbo, ni agbára nla ti o ba iponju re je lesekese,ẹyiti o ti n gbe Kiri fun odun pipe, nje iyen ko
je Iyalenu bi? Eyi ti o dabire, ọ̀pọ̀ èèyàn ló wà nínú ijo lónìí, tí won ń gbádùn ara wọn. Ṣùgbon ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni kò ‘fọwokan’ Olúwa kí won sì pàdé Rẹ̀. Ṣe o jẹ ọkan ninu opo ènìyàn?
ADURA
Baba Ọrun Mo fẹ ni iriri ágbára re nigbagbogbo, Ọgbọn Rẹ ati Oore-ọfẹ Rẹ ni orukọ Jesu Amin
BIBELI KIKA: Máàkù 5:24-30