AS YOUR SOUL PROSPERS

THE SEED

“Beloved, I pray that you may prosper in all things and be in good health, just as your soul prospers.” (3 John 1 : 3)

 

This is the prayer of Brother Paul to all his friends in Christ Jesus to always testify to the faithfulness of God. In fact, God wants you to enjoy prosperity in every area of your life on a daily basis. The only way this will become a reality is by you being committed to the renewing of your mind. We are living in a world that is full of bad news and misinformation, that is designed to contend with faith of the word of God for our lives. This is why your Bible must be your closest companion. The Word of God does not just purify your soul, but it also imparts the right information that you need for a prosperous life. Do not allow the world around you to run your life. Stay in the Word of God until your mind is transformed, pray on it, see it by faith and it will come to reality.

BIBLE READING: Romans 12:2

PRAYER: Oh Lord I will fulfill my destiny in Christ Jesus

                                              BÍ O TI DÁRA FÚN ỌKÀN RẸ

IRUGBIN NAA

“Olufẹ, èmi ngbadura pe nínú ohungbogbo ki o máà dára fún ọ, ki o sí máà wà ní ìlera, àní bí o ti dára fún ọkàn rẹ.” 3 John 1:3

 

Eyi ni adura arakunrin Paulu si awọn ọrẹ rẹ ninu Kristi Jesu lati jẹri nigbagbogbo si otitọ Ọlọrun.  Lotitọ Ọlọrun fẹ ki o gbadun iṣerere ni gbogbo igbesi aye rẹ lojoojumọ. Ọna kan ṣoṣo ti eyi yíó fí di otitọ ni, nipa sisọ ọkàn rẹ dọtun. A ngbe ni aye ti o kun fun awọn iroyin buburu ati àlàyé ti ko tọ, eyi ṣe lòdì si  igbagbọ ninu ọrọ Ọlọrun, fun igbesi aye wa. Eyi ni idi ti Bibeli rẹ gbọdọ jẹ alabarin ti o sunmọ ọ julọ. Ọrọ Ọlọrun kii ṣe lati sọ ọkan rẹ di mimọ nikan, ṣugbọn o tun funni ni alaye ti o tọ, ti o nilo fun igbesi aye rere. Maṣe gba, eniyan inu ayé laaye, lati bá ọ ṣe ètò igbesi aye rẹ. Duro ninu ọrọ Ọlọrun titi ọkan rẹ yio fi di ọtún, gbadura lori rẹ, rii pẹlú igbagbọ ati pe yíó wa di otitọ.

BIBELI KIKA: Romu 12:2

ADURA: Oluwa ran mi lọwọ lati mu ayanmọ mi ṣe ninu Kristi Jesu.  Amin.

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *