AVOID EVERY FORM OF DISTRACTION (2)

THE SEED

“There is only one thing worth being concerned about. Mary has discovered it, and it will not be taken away from her.” LUKE 10:42 NLT

The story of Mary and Martha again reminds us that it is possible to get distracted from being in the presence of God by doing those things we consider as necessary and very important. Looking at this story, the welfare of others is an important ministry and I believe Jesus was not condemning Martha for showing kindness and having the mind to serve others. Welfare Ministry is needed in the body of Christ and we need people to serve in this ministry but this should not in any way take precedence over spending quality time in the presence of God Almighty. Also with our individual lives and daily commitments here and there, from going to our places of work, and school, looking after the family and so on, we should be careful that we do not allow these necessary needs to distract us from what is important in life. Spending time in God’s presence and reading His words daily, is the only thing we should consider as the most important aspect of our daily lives as children of God. We should not allow anything to take the place of our daily devotion to the Lord. We now live in a very fast-paced environment and there are lots of things fighting for our immediate attention which are necessary, but we are being reminded today, that we should not allow these things to become a form of distraction to us from doing the will of God the Father in the capacity He has called every one of us.

BIBLE READING: LUKE 10:38-42

PRAYER: Father, I pray today that you help me to take count on those things that are important in life and help me to focus more on doing your will in Jesus’ name. Amen.

 

 

YẸRA FÚN ONÍRÚURÚ IDIWỌ (APÁ KEJI)

IRUGBIN NAA

“Ṣùgbọ́n ohùn kàn ni a ko le ṣé aláìní. Màríà sí tí yàn ipá rere na, ti a ko sí lé gbà ni ọwọ rẹ”. LUKU 10:42.

Ìtàn Màríà àti Màtá tún rán wa létí pé ó ṣeé ṣe láti yàgò kúrò nínú wíwà níwájú Ọlọ́run nípa ṣíṣe àwọn ohun tí a kà sí ohun tí o pọndandan ti ó si ṣe pàtàkì. Wíwò ìtàn yìí, àbójútó ìtọ́jú àwọn ẹlòmíràn jẹ́ iṣẹ́ iranṣẹ ́ ti o ṣe pàtàkì. Mo sì gbàgbọ́ pé Jésù kò dá Màtá lẹ́bi ní fífi inúure hàn àti níní ọkàn láti sin àwọn ẹlòmíràn. A nilo iṣẹ-iranṣẹ ti o jẹ́ ti iranlọwọ ninu ara Kristi, a si tún nilo awọn eniyan lati ko pa ninu iṣẹ-iranṣẹ yii, ṣugbọn eyi ko yẹ ki o borí lilo akoko dáradára ni iwaju Ọlọrun Olodumare. Pẹlupẹlu igbesi aye olukuluku wa, nipa lílọ bi bọ̀ ojoojumo si ibi iṣẹ wa, ati Ile-iwe, bi i ibojuto idile ati bẹẹ bẹẹ lọ, a gbọdọ ṣọra ki a ma ṣe jẹ ki awọn iwulo pataki yii ṣe idiwọ fún wa kuro ninu ohun ti o ṣe pataki ni igbesi aye wa. Lilo akoko ninu awọn ọrọ Ọlọrun ati wiwa niwaju Rẹ lojoojumọ, nikan ni ohun ti o yẹ ki a gbe yẹwo gẹgẹ bi ohun tí ó jẹ pataki julọ ninu igbesi aye ojoojumọ wa gẹgẹbi awọn ọmọ Ọlọrun. A ko gbodo jẹ́ ki ohunkohun gba ipo ìfọkànsìn wa lojoojumo si Oluwa. Ni bayi a ngbe ni agbegbe ti a nṣe ohùn gbogbo ni kankan ati pe ọpọlọpọ awọn nkan nbere fun akiyesi wa kíákíá; ti wọn si jẹ dandan, ṣugbọn a n ran wa leti loni pe ko yẹ ki a jẹ ki awọn nkan wọnyi jẹ́ idena fun wa lati ṣe ifẹ Ọlọ́run Baba nipa ipa àti agbara ti o fi pe gbogbo wa.

BIBELI KIKA: LUKU 10: 38-42.

ADURA: Bàbá mo gbadura loni pe ki Ẹ ran mi lọwọ lati fojú sí awọn nkan ti o ṣe pataki ninu aye ki Ẹ sí ran mi lọ́wọ́ lati d’ojukọ ṣiṣe ifẹ Rẹ ni orukọ Jesu. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *