BASKING IN HIS PRESENCE

THE SEED

“Thou wilt shew me the path of life: in thy presence is fullness of joy; at thy right hand there are pleasures for evermore.” Psalms 16:11

To be in the presence of God is an awe inspiring, life-changing experience. Moses was never the same after the burning bush and Paul was a changed man after his road to Damascus conversion. For most people the experience of hearing God talk is in short one liners that we remember and cherish. Living constantly in the presence of God begins with the heartfelt renunciation of everything that we understand does not lead to God. Doing this allows us to open a continual conversation with Him, with freedom and in simplicity.  We need only to recognize God intimately present with us in order to give ourselves to Him every moment. God is present all the time and desires our fellowship all the time. God accepts us as we are right now. If you get your heart right, God, through the Scriptures and the Holy Spirit in our life, will take our hand and lead us into His presence from one glory to another.

BIBLE READING: Psalms 16

PRAYER: Let me find everlasting joy always in your presence O Lord

                                                     

                                                   YIYO NI IWAJU RE

IRUGBIN NAA

“Iwo o fi ipa ona iye han mi, ni iwaju re ni ekun ayo wa, li owo otun re ni didun inu wa lailai.” Orin Dafidi 16: 11

Wiwa ni iwaju Olorun je iru iriri iyanu ti n yi aye eniyan pada. Mose ko tun pada ri bakan naa leyin isele  ti ina jo igbe, Paulu di eda tuntun leyin iyipada re ni ona Damascu. Fun opolopo eniyan, iriri won nipa gbigbo ohun Olorun je ohun ti o se iyebiye si won. Gbigbe ni iwaju Olorun nigba gbogbo bere pelu kiko ohun ti ko gbeniro niwaju Olorun sile tokan tokan. Sise eyi ran wa lowo lati le maa ba A soro ni igba de igba ati pelu igboya. A ni lati mo wipe Olorun wa pelu wa, ki a si le fi ara wa fun un nigba gbogbo. Olorun wa pelu wa, o si tun nfe ki a ba ohun dapo ni gbogbo igba, Olorun gba wa bi a ti wa nisisiyi. Bi okan wa ba se deede, Olorun, nipase Iwe Mimo ati Emi Mimo ninu aye wa, yio mu wa lowo, yio si dari wa lo si iwaju re lati inu ogo kan si ekeji.

BIBELI KIKA: Orin Dafidi 16

ADURA: Je ki n ri ayo ayeraye ni iwaju re ni igba gbogbo, Oluwa. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *