Battle For The Mind

THE SEED
“Keep thy heart with all diligence; for out of it are the issues of life.” Proverbs 4:23

There is a lot in the world today that can poison the minds of the people against the things of God. There is legalism, there is the idea that you will give up all of the fun things in life, there are even things like media that twist the Scripture to suite their needs and when you try to share the truth of God’s word with people their minds have been so poisoned that they believe the lies of the world and tell you what you believe is a lie. Always remember that the enemy is out there to turn the minds of the people away from the truth. Know this when it comes to the enemy who is poisoning the minds of the people, they have no intentions on helping the people. The enemy is all about themselves. It is all about control, control the minds of the people and controlling them with lies disguised in half-truths, which are just lies. Be careful what has your mind and your soul, either Christ is in control or Satan.

BIBLE READING: Proverbs 4

PRAYER: I cast out every intentions of sin in my mind in Jesus name

OGUN JIJA TI OKAN

IRUGBIN NAA
“Pa Okan re mo nítorí láti inú re ni orisun iye” Òwe 4:23

Opolọpo ló wà nínú ayé lónìí tó lè mú kí ọkàn ẹniyan se lòdì sí àwọn ife Ọlọ́run. Lara re ni Ilana ofin, erongba Okan ni wipe Iwo yio jowo Gbogbo igbadun re ninu aye bee sini awon ero ayelujara yio túmo bibeli lonà ti yio te araye lorun. Nigba ti o ba gbiyanju Lati Fi otito Oro Ọlorun bo awon eniyan, a ti ba Okan won je Debi pe won yóò gbàgbo pe iro ni oun ti o gbàgbo. Maa ranti ni Gbogbo igba pe ota wa ninu aye Lati mu ki Okan awon eniyan se Lodi si otito. Mọ eyi nigba ti o ba de ọdọ awọn ọta ti o n yi Okan awon eniyan, wọn ko ni ipinnu lati ran awọn eniyan lọwọ.Awọn ọta mo nipa ara wọn nikan. Erongba won ni Lati maa ṣakoso ọkan awọn eniyan nipase iro ti o farape otitọ, eyiti o jẹ irọ lasan. Ṣọra ohun ti o sakoso ọkan ati ẹmi rẹ. Nje Kristi ni tabi Satani?

BIBELI KIKA: Owe 4

ADURA: Mo lé gbogbo erongba ẹṣẹ jade ninu ọkan mi ni orukọ Jesu

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *