BE THE DOER OF THE WORD

THE SEED
“But he who looks into the perfect law of liberty and continues in it, and is not a forgetful hearer but a doer of the work, this one will be blessed in what he does.” James 1:25

The Word of God is full of power for prosperity, but you need to know how to release this power before you can greatly benefit from it. It is not good enough to store up scriptures in your memory. Until transition is made from knowing the Word in the head to practicing it in your daily life, power is not released. There is a difference between the sense knowledge of the Word of God and revelation knowledge of it. The former is simply called mental assent, while revelation knowledge on the other hand propels you to act on the Word of God. Acting on the Word is real faith; it is what triggers God’s moves and powers. The book of James is more of practical and action, God’s word is what we hear and then do. Stepping out this way brings God’s power on the scene, thereby making the impossible possible. Don’t be content with having mere sense knowledge; stay with the Word long enough to receive revelation that will make you act in line. The blessing comes not from the hearing of God’s word, but in the Doing of God’s word, because God said so is reason enough, when the time is right, He will reveal His reasons. But, regardless of whether or not we ever understand the reasons, we are to obey God and be a doer of His word.

BIBLE READING: 1 Samuel 15:22

PRAYER: Oh Lord help me to be a doer of your word

 JẸ OLÙṢE Ọ̀RỌ̀ NÁÀ

IRUGBIN NAA

“Ṣugbọn ẹnití o bá nwọ inú òfin pípé, òfin omiran ni, ti o sí duro nínú rẹ, ti pon ko jẹ olùgbọ ti ngbagbé, bikoṣe oluṣe iṣẹ, oluwarẹ̀ yíó jẹ́ alabukun ninu iṣẹ rẹ̀.” Jakọbu 1:25

 

Ọrọ Ọlọrun kun fun agbara fun iṣerere, ṣugbọn o nilo lati mọ bi o ṣe le tu agbara yii silẹ ṣaaju ki o to le ni anfani pupọ lati inú rẹ.  Kò dára tó láti ko àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ sínú ọpọlọ rẹ.  Titi di iyipada yíó fí wà, lati mọ ọrọ ni ori, tí a o si fi máà mú wá sí ojú ṣe ni  ojoojumọ ayé, agbara ko ti i wà ni itusilẹ. Iyatọ wa laarin imọ ọrọ Ọlọrun lati orí, ati imọ ifihan rẹ.  Awọn ọrọ tí o wà tẹlẹ, nìkan ní a npe ni ọrọ ọpọlọ. Nigbati ti imọ ifihan ni apa keji, n tí ọ lati ṣiṣẹ lori ọrọ Ọlọrun.  Iṣẹ ṣiṣe lori ọrọ náà jẹ Igbagbọ gidi, o jẹ ohun ti o nfa awọn igbesẹ ati awọn agbara Ọlọrun.  Iwe Jakọbu jẹ èyí  ti a le mú wá sí ojúṣe. Ọrọ Ọlọrun jẹ ohun ti a ngbọ ti a si nṣe. Jijade kuro ni ọna yi mu kí agbara Ọlọrun wa sí gbangba, ti o sí mú kí ohun tí kò ṣeé ṣe kí o di ṣi ṣeé ṣe. Maṣe ni itẹlọrun pẹlu nini imọ lori lasan: duro pẹlu ọrọ náà pẹ, lati gba ifihan ti yíó jẹ ki o ṣiṣẹ ni ọnà tí o yé Koo ro. Ibukun ko wa lati gbigbọ ọrọ Ọlọrun, ṣugbọn ninu ṣiṣe ọrọ Ọlọrun. Nítorí pé Ọlọ́run sọ bẹ́ẹ̀ fún eredí tí ó tó, nígbà tí àkókò bá tó, òun yóò ṣí àwọn eredí rẹ̀ payá. Ṣugbọn laibikita boya tabi a ko loye awọn eredi yi, a ni lati gbọràn si Ọlọrun ki a jẹ oluṣe ọrọ Rẹ.

BIBELI KIKA: 1 Sámúẹ́lì 15:22

ADURA: Oluwa ran mi lọwọ lati jẹ olùṣe ọrọ Rẹ.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *