BECOME WHO GOD CALLED YOU
THE SEED
“Then Saul, also known as Paul, was filled with the Holy Spirit; he looked straight at the magician and said…” — Acts 13:9 GNB
Saul became Paul at a defining moment of confrontation. His true identity in God emerged when he rose to face opposition. Just like David became a giant-killer when he confronted Goliath, stepping into destiny often happens in the face of challenges. Many people hold on to their “Saul” identity—safe, familiar, and comfortable. But your divine identity emerges when you stand in faith to overcome obstacles. Step out of comfort and embrace who God has called you to be.
BIBLE READINGS: Acts 13:6–12 PRAYER: Heavenly Father, I embrace the
vision of who You have called me to be. Let me walk boldly in it. Amen.
JẸ́ OHUN TÍ ỌLỌ́RUN PÈ Ọ́
IRUGBIN NAA
“Ṣùgbọ́ n Saulu ( tí a npe ni Paulu) o kún fún Ẹ̀míMimọ,osítẹjúmọ́ọ,osíwípé”IṢẸ́ ÀWỌN ÀPỌ́ SÍTÉLÌ 13:9
Saulu di Paulu ni akoko ìkoraẹnilójú. Ohun tiójẹnítootọnínúỌlọ́runfarahànnígbàtió dìde láti kojú àtakò. Gẹ́gẹ́ bí Dáfídì ṣe di eni ti o pa òmìrán nígbà tó dojú kọ Goliati, bíbọ́ sínú ayanmọ sábà máa ń ṣẹlẹ̀ ni ìkòríta àwọn ìpèníjà. Ọ̀ pọ̀ ènìyàn ló so mọ́ ìdánimọ̀ atijo wọn – nitoripe o je ailewu, tabi ohun ti won mo, tí o si je irọrun. Ṣugbọn idanimọ atọrun rẹ yoo farahan nigbati o duro ninu igbagbọ lati bori awọn idiwọ. Kúrò ninu ibi irọrun ki ogbairuẹnitiỌlọruntipeọlatijẹ.
BIBELI KIKA: Acts 13:6–12.
ADURA: Baba wa Ọrun, Mo gba iran iru ẹnitiopemilatijẹ.Jẹkinrinpẹluigboya ninurẹ̀.Amin.