BLESSED WITHOUT SEEING

THE SEED
“Thomas, because thou hast seen me, thou hast believed: blessed are they that have not seen, and yet have believed.” — John 20:29 KJV

Thomas refused to believe until he saw Jesus.Many believers act like Thomas—waiting to see visible results before trusting God. Jesus says those who believe without seeing are blessed. Faith is thebridgebetweenpromise and manifestation. Believing before seeing releases God’s power to work in your life. Those who trust Him fully experience the joy of His faithfulness. Faith requires trusting God’s promises even when the evidence hasn’t appeared. Don’t wait to see; believe first, and you will receive.

BIBLE READINGS: John 20:24–29

PRAYER: Heavenly Father, even when I can’t see it, I choose to trust in Your promises. Amen.

ALABUKUNFUN NIGBATI O KO RII
IRUGBIN NAA
… Nítorí tí ìwọ rí mi ni ìwọ ṣe gbàgbọ́: alábùkún fún ni àwọn tí kò rí mi, tí wọ́n sì gbàgbọ́ !” Johanu 20:29
Tomasi kò ̣ lati gbagbo afi igba ti o ri Jésù. Opo onigbagbo ni o n huwa bí ti Tomasi, tí o n duro lati ri eri ki won to gba Olórun gbo! Jesu wipe awon ti o gbagbo lai rii di alabukunfun. Igbagbo ni afara ti o wa laarin ileri ati imuse. Gbigbagbo saaju riri n mu agbára Olorun sịsẹ ́ ̣ninu aye re. Awon ti o ba gbaagbo lekunrere yio ni iriri ayo ailopin Re. Igbagbo pèfun gbigekele ileri Olorun bí kò tile ti f’ara han. Mase duro lati rii, koḳ o ̣ gbagbo, iwo yio si rii.

BIBELI KIKA: Johanu 20:24-29

ADURA: Baba wa Orun, bí emi kò tile le
rii, mo yan lati gbagbo ninu ileri Re. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *