THE SEED
“But ye are a chosen generation, a royal priesthood, an holy nation, a peculiar people…” — 1 Peter 2:9 KJV
Every believer is a priest and a king unto God. We are called to stand in the gap, interceding for the lost and representing God to the world. Our priesthood carries the responsibility to pray, share the gospel, and live as examples of Christ’s love. This royal calling is both a privilege and a duty. God has trusted us with the ministry of reconciliation, to be His voice and hands to those who are still in darkness. Our lives must reflect His nature—holy, compassionate, and bold in declaring His truth. The destiny of souls should move us to compassion and action, for we are God’s chosen vessels to bring light to darkness.
BIBLE READINGS: Hebrews 4:14–16 PRAYER: Father, help me to carry the
mark of the Royal Priesthood and stand for lost souls. Amen.
ÌPÈ BÍ TI OLÚ ÀLÙFÁÀ
IRUGBIN NAA
“Ṣugbọn ẹnyin ni iran ti a yàn, olu-alufa, orilẹ-ède mimọ́ , enia ọ̀ tọ…” Peteru Kinni 2:9
Onigbagbo kookan je alufa àti oba fun Olórun. A ti pe wa lati duro gege bi olulaja fun awon ti o sonu ati asoju fun Olórun ni agbaye. Ipo alufa wa ni ojuse láti gbadura, polongo ìhìnrere, ki a si gbe gege bí apeere ife Kristi. Ìpè olá yii je anfaani àti isẹ́.̣ Olórun ti fi ise onilaja le wa lowo, lati je ohùn àti oẉ ó ̣Re si awon ti o ku si okunkun. Aye wa gbodo fi iwa Re- ti o je Mimo, aanu, ati ti Igboya lati so otito nípa Re han. Igbala okan awon eniyan gbodo pe wa n’ija fun aanu ati ise, nitori pe a je ohun elo lati mu imole wa si’nu okunkun.
BIBELI KIKA: Heberu 4:14-16
ADURA: Baba, ran mi lowo lati má a ru ami Alufa ti o lola ati lati duro fun awon okan ti o sonu. Amin.