Can A Child Of God Compromise?

THE SEED
“Ye shall observe to do therefore as the Lord your God hath commanded you: ye shall not turn aside to the right hand or to the left.” Deuteronomy 5:32[KJV].

God our Father is gracious, merciful and compassionate. Yet, He will never for any reason compromise. In every case that there is a need to exercise His authority and power on any matter or anybody, He is not a respecter of anyone. His word told us in Matthew 5:48[KJV] “Be ye therefore perfect, even as your Father which is in Heaven is perfect” He meant every word of it, so as children of God, we have to obey Him completely and act by His words. We cannot even pretend because He can’t be deceived or mocked He sees us to the deepest place of our heart, nowhere to hide that he does not know, reference to king David that killed Uriah so to commit adultery with the wife called Bathsheba[2nd Samuel 7:8] God did not spare him, despite his plea, the child died. Jonah too refused God’s instruction to go to Nineveh to preach the gospel, a whole ship almost capsize until he agreed to obey the instruction of God and he was protected safely to where he was sent to deliver Gods message, yours and mine might be different to the ones mentioned. Let us search our hearts and amend our ways and be holy as our Lord is.

PRAYER
Help us Lord to always remember the death of Jesus your only begotten son on the cross to remain steadfast and not compromise. Amen.

BIBLE READINGS: Deuteronomy 5: 1-33

NJE OMO OLORUN HA LE GBOJEGE?
IRUGBIN NAA
“Nitorina ki enyin ki o maa kiyesi ati se bi Oluwa Olorun nyin ti pase fun yin, ki eyin ki o mase yi si otun tabi si osi.” Deuteronomy 5:32.

Olorun, Oloreofe, alaanu, onipamora ni baba wa, sugbon ki yio gbojege. Nigba ti o ba ye ki o lo ipa ati agbara re lori ohunkohun tabi enikeni. Kii se ojusaju enikeni. Oro re so fun wa ninu Matteu 5:48. Nitorinaa, ki eyin ki o pe, bi Baba yin ti mbe li orun ti pe. Gege bi omo Olorun, a gbodo gboran ki a si tele oro Re. A ko le tan an je nitori a ko le tan tabi gan Olorun, O ri wa titi de ikoko okan wa, ko si ibi ti a le farapamo si kuro ni iwaju re ti On ko mo. E je ki a ranti oba Dafidi ti o pa Uriah ki o ba le ba aya re ti a n pe ni Bathsheba se agbere (II Samuel 7:8) Olorun ko daa si, pelu gbogbo ebe re, omo naa ku. Jonah bakan naa ko ase Olorun lati lo si Ninefe lati waasu ihinrere, oko oju omi fere ri titi o fi gba lati tele ase Olorun, o si dabobo o titi o fi de ibi ti Oluwa ran si. O see se ki temi ati tire yato si awon ti a daruko. E je ki a ye okan wa wo ki a si tun ona wa se, ki a je mimo bi Olorun wa ti je mimo.

ADURA
Ran wa lowo Olorun, ki a le maa ranti iku omo re nikan soso Jesu Kristi lori igi agbelebu, ki a le duro sinsin ki a ma si gbojege. Amin

BIBELI KIKA: Deuteronomi 5: 1-33

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *