CHOOSE THE NARROW WAY

CHOOSE THE NARROW WAY
THE SEED
“You can enter God’s kingdom only through the narrow gate… the road is difficult, and only a few ever find it.” — Matthew 7:13– 14 NLT
The way to heaven is narrow—not because God wants to keep people out, but because it requires intentional choices and sacrifices.
The broad way is easy and crowded, but it leads to destruction. Every step on the
narrow road is a step of faith, and though the path may be lonely at times, you are never walking alone. God’s grace sustains those who choose to follow His way, and His reward is eternal. Don’t be swayed by the noise of the crowd; stay focused on your destination.
Walking the narrow path demands holiness, discipline, and steadfastness in faith. Make the daily choice to follow Christ, even when it is not popular.
BIBLEREADINGS: Matthew7:13–21
PRAYER: Father, strengthen me to remain steadfast on the narrow way that leads to life. Amen.

YAN ÒṆ ÀTÓÓRÓNÁÀ
IRUGBIN NAA
“Ẹ ba ẹnu-ọ̀nà tóóró wọlé; gbòòrò ni ẹnu- ọ̀nà náà, àti oníbùú ni ojú ọ̀nà náà tí ó lọ sí ibi ìparun, ọ̀ pọ̀ lọpọ̀ ni àwọn ẹni tí ń bá ibẹ̀ wọlé. Matiu 7:13
Tóóró ni ona si Orun- kii se nitori pe Olorun fe ti awon enia mo ita, sugbon o pe fun fi yiyanohuntiodarapeluifaraji.Onagbòòrò naa rorun, be e ni o gb’èrò sugbon o to’ka si iparun.
Gbogbo igbese ní ona tooro je ti igbagbo bí
o tile máa n dá ni igba miran, iwo kò nikan rin in. Oore ofe Olorun gbé awon ti o ba yan lati tele Ona Re ró, èrè Re si je ti ayeraye. Iwo mase wo ariwo oja, tejúmó ̣ ibi ti iwo n ló.
Ririn ni oju Ona tooro naa pe fun iwa mimo, iko’ra eni ni ijanu àti iduro sinsin ninu igbagbo. Yan lati tele Jésù lojoojumo bí won kò tile kaa si.
BIBELI KIKA: Mathew 7: 13-21

ADURA: Baba, gbe agbára Re wo mi ki n le
duro ni Ona tooro ti o lo si iye. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *