CHRISTIAN’S HOSPITALITY

THE SEED
“But a lover of hospitality, a lover of good men, sober, just, holy, temperate;” Titus 1:8

Christian hospitality first welcomes Jesus into your heart, then into our homes. The context of Christian hospitality is love. Love, first for what Christ has given you with the recognition that everything you have is a gift from Him and belongs to Him. Second is love for others. Hospitality is allowing God to break through the narrowness of our own fears and opening our hearts. It is learning to genuinely care about people. Hospitality also requires generosity, wherein we begin to loosen the grip of those distinctions between what is mine and what is yours. Christian hospitality teaches that people have priority over property. Relationships matter more than a neat and clean house. Jesus was not impressed by a beautiful home, clever decorating, and special cooking. Jesus is impressed with those who put him first and experience joy in serving Him. By exercising your gift of hospitality you have the opportunity to have a great influence for the Lord.

BIBLE READING: Titus 1

PRAYER: Correct my misdeeds O Lord in places am yet to show love to my neighbour

 

IWA IGBALEJO KRISTENI

IRUGBIN NAA

“Bikose olufe alejo sise, olufe awon eniyan rere, alairekoja, olooto eni mimo, eni iwontunwonsi.” Titu 1:8

Iwa igbalejo Kristeni, akoko, pe Jesu wole sinu okan re ati si inu ile re. iwa gbigba alejo kristeni ni ife. Ife, lakoko  fun ohun ti Kristi ti fi fun o ati fifihan wipe ohun gbogbo ti o ni je ebun lati odo Re ati wipe tire ni won nse. Ekeji, o je ife fun omonikeji. Gbigba alejo ni ki a gba Olorun laaye lati mu eru wa Kuro, ki o si si okan wa. O je kiko lati maa toju awon eniyan tokantokan. Gbigba alejo tun je iwa fi funni eyi ti n mu ni gbagbe iyato laarin eyi ti n se temi ati eyi tin se tire. Iwa gbigba alejo kristeni ko wa wipe awon eniyan ni ohun ti won feran ju ohun ini won lo, ibasepo dara ju ile ti o mo, ti o si titun lo. Jesu ko wo ile ti o rewa, awon ohun ti a se ni oso ati ounje aladidun. Sugbon inu Re dun si awon ti o fi Tire saaju, ti won si ni ayo ninu sisin In. nipa lilo ebun gbigba alejo re, o ni anfani lati jere okan fun Olorun

BIBELI KIKA: Titu 1

ADURA: Pa asise mi re Oluwa, ni awon ibi ti nko tii fi ife han si omonikeji mi. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *